Ojo nla l'ojo ti mo yan Olugbala l'Olorun mi (Yoruba hymn)

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 23. 03. 2016
  • Ojo nla l'ojo ti mo yan Olugbala, l'Olorun mi
    O ye ki okan mi yo, ko si ro iyin naa ka le.
    Chorus: Ojo nla l'ojo naa, ti Jesu we ese mi nu.
    O ko mi kin ma gbadura, kin ma sora, kin si ma yo
    Ojo nla l'ojo naa, ti Jesu we ese mi nu.
    vs 2. Ise igbala pari naa, mo di t'Oluwa mi l'oni
    Oun lo pe mi ti mo si je, mo f'ayo je pe mimo naa.
    Chorus: Ojo nla l'ojo naa, ti Jesu we ese mi nu.
    Vs 3. Eje mimo yi ni mo je, f'eni to ye lati feran,
    Je k'orin didun kunle re, nigba mo ba nlo sin nibe.
    Chorus:::Ojo nla lojo naa, ti jesu we ese mi nu.
    Vs 4. Simi aiduro okan mi, simi le Jesu Oluwa,
    Tani je wipe aiye dun, ju odo awon angeli.
    Chorus: Ojo nla l'ojo naa
    Vs 5. Eyin orun gbo eje mi, eje mi ni ojojumo,
    Emi o ma so d'otun titi, Jesu yio fi mu mi rele.
    Chorus: Ojo nla l'ojo naa, ti Jesu we ese mi nu...
    AMIN.
    Thank you for watching, God bless you. Please feel free to LIKE, SHARE AND SUBSCRIBE!!!!!!!!!!!! You can follow me on IG- @mrs_akin,
    Like my page on facebook 'HymnswithAdeola',
    email address: aolugbesan@gmail.com.
    If you would like to do collab video with me, feel free to emai me at aolugbesan@gmail.com or singwithadeola@gmail.com
    GOD BLESS YOU!!!
    My singles now available on any digital store. They includes some great CLASSIC HYMNS. To download, "Olugbala ni Olorun mi", and "All is well" please kindly visit your digital store; iTunes, Google play, spotify, Amazon and so on. You can also type in "Adeola Akinrinlola" in your digital store's search bar. Remember to share with your families and friends.
    iTunes link
    All Is Well - Single by Adeola Akinrinlola
    itun.es/ca/Jkiphb
    Google Play link- play.google.com/store/music/a...
    iTunes link- Olugbala Ni Olorun Mi - Single by Adeola Akinrinlola
    itun.es/ca/Kbiphb
    Google Play link- play.google.com/store/music/a...
  • Zábava

Komentáře • 37