Ija d'opin ogun si tan (yoruba hymn)
Vložit
- čas přidán 4. 09. 2024
- vs 1. Ija d'opin ogun si tan
Olugbala j'agun molu
Orin ayo la o mako
Alleluija!
2. Gbogbo ipa n'iku ti lo
sugbon Jesu f'ogun re ka
Aiye e ho iho ayo
Allelujah
3. Ojo meta naa ti koja
O jinde kuro ninu oku
e f'ogo f'Oluwa wa
allelujah
4. O de won orun apadi
o silekun orun sile
e korin iyin segun re
allelujah.
5. Jesu nipa iya to je
gba wa lowo oro iku
ka le ye ka si ma yin O
allelujah.
My singles now available on any digital store. They includes some great CLASSIC HYMNS. To download, "Olugbala ni Olorun mi", and "All is well" please kindly visit your digital store; iTunes, Google play, spotify, Amazon and so on. You can also type in "Adeola Akinrinlola" in your digital store's search bar. Remember to share with your families and friends.
iTunes link
All Is Well - Single by Adeola Akinrinlola
itun.es/ca/Jkiphb
Google Play link- play.google.co...
iTunes link- Olugbala Ni Olorun Mi - Single by Adeola Akinrinlola
itun.es/ca/Kbiphb
Google Play link- play.google.co...
God bless you
Happy Easter
Irede Pretty thank you so much. I wish you the same.
Adeola where are you based? I come across your song on utube, for the first time, it is fantastic. I played it over n over again. You are a gifted soul. Shalom!