Ore aiye ki lo ja mo? (Yoruba hymn)

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 4. 09. 2024
  • 1. Ore aiye ki lo ja mo? Oun asan ni mo mo si, ko si ore Kan, bi Jesu. Alawo ko, Olorun ni, awole ko, Olorun ni, enia ko, Olorun ni.
    2. Jeje mo joko, n'ile mi, esu wa deru b'okan mi, sugbon Jesu da mi sile. Nwon ni mo ku l'araiye no, nwon loti ku, l'araiye nso, sugbon Jesu gbemi leke.
    3. Alairise ko ma binu, alaisan ma so reti nu, Jesu yio mu yin l'ara da. Alawo ko, Olorun ni, onisegun ko, Olorun ni, enia ko, Olorun ni.
    4. Nje mo ro mo Jesu mi, emi ki o fi o sile, b'o ti wu ki 'ji na le to. Babalawo ko, Olorun ni, onitira ko, Olorun ni, akunleyan ni mba mi ja.
    5. Oye kin fi Jesu s'ore kosi ore Kan, bi Jesu, Jesu to fe wa d'oju iku. Ateyanrin ko, Olorun ni, alagbigba ko, Olorun ni, enia ko Olorun ni.
    6. K'a f'ogo fun Baba l'oke, K'a f'ogo fun Omo pelu, ogo ni fun Metalokan. Olosanyin ko, Olorun ni, aworawo ko, Olorun ni, Jesu nikan l'o to ke pe.
    Amin.
    My singles now available on any digital store. They includes some great CLASSIC HYMNS. To download, "Olugbala ni Olorun mi", and "All is well" please kindly visit your digital store; iTunes, Google play, spotify, Amazon and so on. You can also type in "Adeola Akinrinlola" in your digital store's search bar. Remember to share with your families and friends.
    iTunes link
    All Is Well - Single by Adeola Akinrinlola
    itun.es/ca/Jkiphb
    Google Play link- play.google.co...
    iTunes link- Olugbala Ni Olorun Mi - Single by Adeola Akinrinlola
    itun.es/ca/Kbiphb
    Google Play link- play.google.co...

Komentáře • 15