Bi ao ti e gbo ede ti efi nbawa soro, ani Igbagbo pe kiise pe e koro oju si fidio yí. Boti wu kori, Adupe lowo yín;Àdúrà wa ni wipe, Eledua yo lanan Irẹ fun yin, onan Ayo yo la fún yin
Omo ikirun ni mi omo ile Eesa agunbe onile obi egbon baba mi ni Eesa to wa Lori oye bayi, baba iya mi sini ogbontarigi ode Lasisi Olakangudu ki ile ma gberi fun baba iya mi ati baba babami Eesa Adeleke ano awon okunrin takun takun niyen. E shey atokun ti e de ile babami. E bere odofin ode ikirun baba logoja ki e shey iwadi de odo wan naa.
En fi ogun no ra yin is illiteracy if you ask me. This is why most yoruba are scared to do Isese, but go join Muslim or Christian religion. Stop scary people by using ogun to test each other
After God (Oludumare) are the Orishas like Ogun. Arabic and Jewish Allah and Jehovah are equivalents of our African Orishas like Ogun and Orunmila, not superior.
Konibaje lase edumore
Olootù ekù isè ilakayè ekù orò ilù
Fìďiò yin tì mà'nsà eerè pupò jù
E jò èjè kì ò ma lò bì ogbòn isèjù tà'àbì wàkatì kàn..
Eledumarè yì ò mà'bòyin laashirì
Lol... Eseun lọpọlọpọ fun Ife alailegbe ati ifowosowopo yín. Lagbara Ọba Oke, Inun yín yo dun kale.asiri yín kọ́ni tu lailai
❤
Kabo bikear from Timilehin John Aderemi
Ajuba ẹyin Agba
1st
Ope pàtàkì lowo yín sir
Well done sir
Ope pàtàkì lowo yín fun Ife àti ifowosowopo
🎉 Welcome back am always enjoying your program and appreciate you for going to my City Efon - Alaaye in Ekiti State to interview our Balode.
Yo ma dun fun yin lagbara Eledua
Thanks for the great work
Eseun lopolopo, sir
E ku ise o, kudos❤
Eseun lopolopo sir, igba yin kọ́ni darù lagbara Eledua
Eku Ise Takuntakun ❤
Well done Sir
Eseun sir
Welcome back
Ajuba yin o
La meilleur émission Bikear tv ❤❤❤
Bi ao ti e gbo ede ti efi nbawa soro, ani Igbagbo pe kiise pe e koro oju si fidio yí. Boti wu kori, Adupe lowo yín;Àdúrà wa ni wipe, Eledua yo lanan Irẹ fun yin, onan Ayo yo la fún yin
@@BikearTv amin ooo
Omo ikirun ni mi omo ile Eesa agunbe onile obi egbon baba mi ni Eesa to wa Lori oye bayi, baba iya mi sini ogbontarigi ode Lasisi Olakangudu ki ile ma gberi fun baba iya mi ati baba babami Eesa Adeleke ano awon okunrin takun takun niyen. E shey atokun ti e de ile babami. E bere odofin ode ikirun baba logoja ki e shey iwadi de odo wan naa.
Daada yin kọ́ni baje lagbara Ọlọ́run Oba, yo ma juyin se
Your tok well
À'nrèetì apà kèejì nì àipè
Odara sir, Eseun lọpọlọpọ
En fi ogun no ra yin is illiteracy if you ask me. This is why most yoruba are scared to do Isese, but go join Muslim or Christian religion. Stop scary people by using ogun to test each other
Eseun sir
Iṣẹse is not a religion. Therefore, you are not invited to join, nor will you be entice to join. Continue with your Christianity or Islam.
Eku irolè èku éto Olorun yo man ranyi lowo
Se kosi nkan tojèwipé timopé ilèsè yin won kiyi dami lohun
Ema binu, Ise pi fun wa lenu ijo meta yi. Ebawa fi atejise ranse.Eseun fun Ife alailegbe ti eni fún wa.
After God (Oludumare) are the Orishas like Ogun. Arabic and Jewish Allah and Jehovah are equivalents of our African Orishas like Ogun and Orunmila, not superior.