Ògbójú Ode : Iwin wá nínú Igi to wá leyin Ile mi títí di oni| Lọ́jọ́ tí age igi ni Ilu Eko Ende.

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 12. 05. 2024
  • Iwin wá nínú Igi to wá leyin Ile mi títí di oni/ Lọ́jọ́ tí age igi ni Ilu Eko Ende, Isaasu Ọbẹ̀ wá nínú Igi tí age Àṣírí bí mo ńṣe nlo ẹran ETA láti ṣe iṣẹ́ bibo àṣírí fún àwọn alaini
  • Zábava

Komentáře • 35

  • @adebisiadedoyin8570
    @adebisiadedoyin8570 Před 20 dny

    Eko Ende, Eko Ajala, Inisha, Okuku,. I remember back in the days.

  • @FolorunshoRonkeolufemi

    ASE ASE Ase

  • @opeyemioluseye3934
    @opeyemioluseye3934 Před měsícem +1

    I like the Baba Oluode, he is soo confident...
    We want more from him.
    Weldone sir 🙌

  • @olawaleakanbi3099
    @olawaleakanbi3099 Před měsícem +2

    Iwájú Iwájú lopa ebiti resi Iwájú Iwájú ni bikear tv yíò ma lọ

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Ase wá! Eseun lopolopo sir

  • @ojojulius191
    @ojojulius191 Před měsícem +3

    Please akika is pangolin if I’m correct right?
    Well done sir Eku eto
    We really love your program

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem +1

      We love you too sir. Eledua yo tẹ yín siwaju

  • @SupremeAfricaKing
    @SupremeAfricaKing Před měsícem +1

    Eku eto. Ewa ati esin Yoruba ko ni paru. Thanks bro love your program. Will definitely support soon.

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Adupe fún oro iwuri yin

  • @SamsonMoses-wf3fv
    @SamsonMoses-wf3fv Před měsícem +1

    ❤❤Eku e,to iwaju iwaju ni I lese bekia television yio ma lo amin

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Ase wá! Adupe lopolopo fún Ife yin sir

  • @TheAyanrinde
    @TheAyanrinde Před měsícem +1

    Onì igbà Kan Nnà tì mò babà Kan sorò nipà igbinyanjù Orò ilè aiyè mì..
    Amò Owò tì woñ bèrè fun nù tì pojù..

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Ok.May be the challenge is also big ma

  • @user-mi5lw8sj9v
    @user-mi5lw8sj9v Před měsícem +1

    Hello, Oro Oluode Yi Lo Jeki N'mo Wipe Mo Ti Sunmo Iwin Ri, Ni Owo Ile Su Ferefe Mo Gbo Orun Re, Ori Mi Wu, Otutu Si Mumi, Oku Ni Mo Koko Ro Si O Nkoja Lo, Ara Mi Rewesi , SUNGBON Oro Baba Jeki O Han Simi Wipe Iwin Ni Ki Ise Oku Eniyan ... Kabiyesi Eleda Ohungbogbo.. Iba Re O To Komiyo. Ni Burkina Faso Ni O... Awise, Aminase 🙏.

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Aba yin dupe lowo Eledua, Oba to ni Aye kọ́ni pada leyin yin.

  • @TheAyanrinde
    @TheAyanrinde Před měsícem +1

    Òlòotu eli isè ekù gbògbò làlà koko janjan lori Ishè atì ashà ilè yorubà..tì è ò fè è kò pàrun un
    Eledumarè yiò mà à fun yin sè.
    Mòfè pè e yin sì aki e kàn pàtaki nì ò

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Thanks . You may send such to our WhatsApp number 08075633424. Message only sir.

  • @AKTVChennel
    @AKTVChennel Před měsícem +1

    Bikear Tv i always proud of you

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Eseun Baba mi, Eledua kọ́ni fiyin sile sir

  • @adebisiadedoyin8570
    @adebisiadedoyin8570 Před 20 dny

    one man catch Maagun(thunderbolt), it was in this Eko Ende that they separated them after all other voodoo peoples can't do it

  • @Mathew59
    @Mathew59 Před měsícem +1

    ❤❤❤❤

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Adupe fún Ife àti ifowosowopo yín. Àjíǹde ara yo ma je yín o

  • @olayiwolaabiodun2754
    @olayiwolaabiodun2754 Před měsícem +1

    E ku ise takuntakun

  • @emmanuelwakanda8360
    @emmanuelwakanda8360 Před měsícem

    😊 ASE waa

  • @TimileyinJohnjimoh-fm8lt
    @TimileyinJohnjimoh-fm8lt Před měsícem +1

    Bikear kabo se dada le de se nkan se Omo re

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Lol.. Adupe ó, Layo lade ó!

  • @AyotundeOlaoye-wg4bi
    @AyotundeOlaoye-wg4bi Před měsícem

    Eku eto sir

  • @truthsquestions1532
    @truthsquestions1532 Před měsícem +1

    ❤❤❤

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Ibà ńlá fún yín sir.Eledua kọ́ni fiyin sile sir

  • @olusegunajibade2024
    @olusegunajibade2024 Před měsícem +1

    Kudos❤❤❤

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Ibà yín sir, Eseun lọpọlọpọ

  • @iteoluwa5198
    @iteoluwa5198 Před měsícem +1

    ❤❤❤❤

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před měsícem

      Aki yin fún Ife yin.Eledua yo gbo Àdúrà yin sir