@@BiodunOlawuyi ẹ jẹ́ kín kọ́kọ́ bá ènìyàn méjì sọ̀rọ̀ na, Ọmọ bíbí Ìlú ÌMÈSÍ-ILÉ ni mí ní ìpínlẹ̀ Osun Ariin ìlú méjì ni wọ́n já ogún Èkìtì parapọ̀ na, Ìlú ÌMÈSÍ-ILÉ àti Ìlú Ìgbájọ ìlú méjèèjì sì wá ní ìpínlè ọ̀sun. Àwọn nkan ti ẹ má rí nínú igbó tí wọ́n ti ja ogún na ni 1.àga Ògèdèngbe, 2. omi Fẹ̀jẹbọ́jú, 3. Igi pèrùgún méjì ìkan fún àwọn Ọ̀yọ́ lábẹ́ Ààrẹ Látóòsà, ìkejì fún àwọn Ekiti parapò lábẹ́ Ògèdèngbe, 4. Igi faragbọta, 5.ojúbọ Ògún. Oṣù Kẹsan lọ́dọdún ni wọ́n má ńṣe ìrántí àwọn akoni tó kú nínú ogun na. Ẹlè bámi sọ̀rọ̀ lórí Facebook OLUJIMI JACOB KOLAWOLE.
Yoruba elders with Wisdom...I really enjoyed this video
We are great people... we need to always remember that! I am proud of my people
Eku ohun ama juyin se ooo, God bless u and baba for this Enlightenment.
Thank you brother, you're doing a great job. God will continue to bless all your doings!Amen
Ifa is beautiful, full of wisdom and I really wish we could start teaching it in Yourba schools.
Great teaching 👏. Baba is a great teacher he deserves a playlist on the channel.
There is a play list for him already. Thanks.
Biodun olawuyi, you shall live long. Thanks a bunch
Àṣẹ Èdùmàrè. Thank you.
Mo gbadun itan yii gan ni oooo.Ese pupo!
Ẹ ṣeun sir.
Hummmm.oro agba...eseun oo
Thanks a bunch. I love dis
Any time I visit Nigeria these 2 men I must spend days with them... i always learn from his videos full of wisdom
The words of the elders are golden...wise words
Mr. Abiodun Olawiyi! Olodumare bless you aseeee
I've watched this like 10 times, and I've sent this to many. They are life lessons that all Yoruba citizens ought to heed.
Thank you sir.
Hunnnn,Eko na ju Meta oooo
Fantastic .
Great words of wisdom to always cherish
Eku imo ati oye.
Interesting insights and peaceful way to live our lives thanks as usual I’m from ogbomoso too I hope ilu iregba oja is the one under ogbomoso?
Yes.
Thanks my brother,i would like to talk with u too;as brother!
@@akanmujohnson66 Here is my contact: 08050386380.
Pls how can I get dat ogidan book...and what talks about..it's write in yoruba
The book is written in Yoruba. It is available on Amazon, Google Books, & Barnes and Noble.
It is a detective story.
It is a detective story.
How can one worship his ori?
Kindly call bàbá on 08037285523
@@BiodunOlawuyi thanks
Mr. ABIODUN OLAWUYI
Oòtí de ìlù ÌMÈSÍ-ILÉ ni ìpínlẹ̀ Osun, ìlú yí ni wọn ja ogún Èkìtì parapọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ sì ogun kiriji,
Ẹ ṣeun. Ṣé ọmọ ìlú náà ni yín? Yóò dára bí ẹ bá leè ṣe atona mi de ìlú náà, àti ẹni tí mo leè lọ bá ní ibè fún ifi ọ̀rọ̀ wá ni lénu wò.
@@BiodunOlawuyi ẹ jẹ́ kín kọ́kọ́ bá ènìyàn méjì sọ̀rọ̀ na,
Ọmọ bíbí Ìlú ÌMÈSÍ-ILÉ ni mí ní ìpínlẹ̀ Osun
Ariin ìlú méjì ni wọ́n já ogún Èkìtì parapọ̀ na,
Ìlú ÌMÈSÍ-ILÉ àti Ìlú Ìgbájọ ìlú méjèèjì sì wá ní ìpínlè ọ̀sun.
Àwọn nkan ti ẹ má rí nínú igbó tí wọ́n ti ja ogún na ni 1.àga Ògèdèngbe, 2. omi Fẹ̀jẹbọ́jú, 3. Igi pèrùgún méjì ìkan fún àwọn Ọ̀yọ́ lábẹ́ Ààrẹ Látóòsà, ìkejì fún àwọn Ekiti parapò lábẹ́ Ògèdèngbe, 4. Igi faragbọta, 5.ojúbọ Ògún.
Oṣù Kẹsan lọ́dọdún ni wọ́n má ńṣe ìrántí àwọn akoni tó kú nínú ogun na.
Ẹlè bámi sọ̀rọ̀ lórí Facebook OLUJIMI JACOB KOLAWOLE.
@@olujimikolawole6240 Kò burú sir. Ẹ ṣeun.
Please i need this baba number
08037285523