THIS IS RIGHT TIME TO FIGHT FOR YORUBA LIBERTY. YORUBAS JUST WAKE UP NOW YORUBA NATION WILL SURELY ACTUALISE THIS PERIOD NOO OTHER TIME. THIS IS THE PERIOD THOSE GENERATION COMING DON'T KNOW WHAT WE ARE SAYING. MAY GOD BLESS YOU OMO YORUBA RERE. . YORUBA NATION NOW.
Dupe Onitiri, Jezebeli ode oni ni, Ganiyu Adamu ati awon Afenfebi ni Kora ,Datani ati Abiramu. Gbogbo awon wonyi igbeyin won ko dara be gege lo ma ri fun won.
Olorun ko si leyin alabosi alabomooru, eyii lo n ki asiri gbogbo won maa tu faye ri. Akanda Olodumare ni Sunday omo Adeyemo,Olorun ni Atona fomo Adeyemo.
I hope the old ‘Wild Wild West’ wild not resurrect in Yoruba this time ‘cause we need to take care of all these useless self proclaimed leaders. I have the list of all of them
Igba ti baba yi sọrọ daada ba yi, kin lo wa de ti wọn o fi wa lẹ yin ẹ yin tẹ nja a fun ilẹ yoruba, sugbọn sa ni agbara Ọlọrun gbgb awọn ti wọn pe ra wọn ni Afẹni fẹre to jẹ pe Afẹni fẹbi ni wọn aara ni o pa gbgb wọn Adebsyọ Idowu
It's a pity that Nigeria is a lawlessness country, because all These burnt vehicles have no insurance coverage. This can not happen in overseas. If you drive your vehicle without insurance coverage for 3 months. The vehicle will be impounded by the police. And you will pay heavily because you can recover your vehicle. But in Nigeria, may be, Three 3, out of 10 pay the insurance coverages. In case of accident, how do feel vehicles owners be can be compensated?? Definitely there be no compensation..
Oluwa Adurotie ; Oluwa a di e mu. Gbogbo Adura Evangelist Michael ni orile ede Isreal a wa si imuse lori re. Ko si oun buruku ti yo sele si e ni oruko Jesu. Ma Ranti ni Igba gbogbo pe baba 1010 ko sun rara, nitoripe eni iriju Olorun ni
may God bless mr shobuyi, more blessing ijn , eseun pupo ibi ti eti mu owo phone ti e bawa ra fun arole baba 10 10 jp obalola , olorun afi opo ropo , may thy lord continue to bless ur work ijn ,
O dàbí ẹnipe ọrọ kìí tètè yé àwa ọmọ Yorùbá. Tinubu ko so fún ẹnikẹ́ni télè pé òun fẹ wá gba ọmọ Yorùbá là. O so pé ibiti Buhari fi ìjọba ti sí ní oun ti máa túnbọ̀ tẹ síwájú sí. Ṣe Tinubu ko sí láyé ni ìjọba Buhari ti àwọn Fúlàní npa kúkúrú pa gigun ní ilẹ Yorùbá ti kò sòrò. Àwa ni kí a mọ̀ bi a ṣe máa yo ara wa kúrò l'oko ẹru wọn.
Yoruba nation is a sure banker whether they like it or not. Afenifere is doing what they are doing out of envy and jealousy. Infact, they did not support president Tinubu election, and this was done also out of jealousy and envy. They have betrayed Baba Awolowo and yorubas.
Tnx baba Sobuyi. God will continue to bls you. Omo baba 1010, oba lola e ku se..God will uphold you.
Baba Shogunyi thank you. God bless you and your family.
Adupe Lowo yin SIR Agba yin adale ooooo Ese gan SIR Apo yin Koni kan isale apo eunkan SI adupe pupo SIR ❤❤❤
BEENI ooooo OMO AROLE BABA 10 10 Eku ETO Ekabo OMO ODO RERE well come back My SON ❤❤❤❤
YORUBA Nation no going back laseeedumare one love IBUKUN ni fun Ori EDE mi YORUBA
Well done my brother for good job ❤❤❤❤❤
THIS IS RIGHT TIME TO FIGHT FOR YORUBA
LIBERTY. YORUBAS
JUST WAKE UP NOW YORUBA NATION WILL SURELY ACTUALISE
THIS PERIOD NOO OTHER TIME.
THIS IS THE PERIOD THOSE GENERATION COMING DON'T KNOW WHAT WE ARE SAYING.
MAY GOD BLESS YOU OMO YORUBA RERE. . YORUBA NATION NOW.
Dupe Onitiri, Jezebeli ode oni ni, Ganiyu Adamu ati awon Afenfebi ni Kora ,Datani ati Abiramu. Gbogbo awon wonyi igbeyin won ko dara be gege lo ma ri fun won.
But Dupe omo ale and Gani Adam must not go unpunished in Jesus name
Baba thank you sir God bless you sis
More blessings sir mr shobuyi
Olorun ko si leyin alabosi alabomooru, eyii lo n ki asiri gbogbo won maa tu faye ri.
Akanda Olodumare ni Sunday omo Adeyemo,Olorun ni Atona fomo Adeyemo.
Nice one 1010
Thank you very much, baba Sowuyi. May God bless and replenish your purse evermore.
I hope the old ‘Wild Wild West’ wild not resurrect in Yoruba this time ‘cause we need to take care of all these useless self proclaimed leaders. I have the list of all of them
Merci Beaucoup to BABA SOBUYI, Thank you, Ese Pupo Baba long life Sir, Well done my Brother 1010,. Yoruba People's Nation.
Igba ti baba yi sọrọ daada ba yi, kin lo wa de ti wọn o fi wa lẹ yin ẹ yin tẹ nja a fun ilẹ yoruba, sugbọn sa ni agbara Ọlọrun gbgb awọn ti wọn pe ra wọn ni Afẹni fẹre to jẹ pe Afẹni fẹbi ni wọn aara ni o pa gbgb wọn
Adebsyọ Idowu
Won fe o won ko o, Yoruba nation is sure. Ile Orile-ede Yoruba o dandan . Oba Lola o ni te beni oju Koni ti e.
God bless you sir
God bless Bàbá Sobuyi abundantly for advancing the Kingdom of Yorùbá Nation.
Yoruba Nation now ❤❤❤❤❤❤
Yoruba wake up let speak out and fight for our yoruba nation
Sugbon Pa Adebanjo le nlo nigba idibo to koja. Ti gbogbo omo Yoruba ko ba dara afi eyin nikan. Ero re o.
Arole, a day without you is an incomplete day. I'm glad you are back. Olodumare a mu wa de ile ileri. Amin Ase
Amin and don't forget to thanks mr shobuyi ❤one love
It's a pity that Nigeria is a lawlessness country, because all These burnt vehicles have no insurance coverage. This can not happen in overseas. If you drive your vehicle without insurance coverage for 3 months. The vehicle will be impounded by the police.
And you will pay heavily because you can recover your vehicle.
But in Nigeria, may be, Three 3, out of 10 pay the insurance coverages. In case of accident, how do feel vehicles owners be can be compensated?? Definitely there be no compensation..
Baba Shobuyi owo yin yo ma lo so ke owo yin ko ni wa le lailai eni gbe sa jo ataya ati awon omo yin lapapo ni ase Edumare be ni yo ri.
ASIRI WON TU PEREPERE NITORI awon ALALE Ti towo bo won lenu AWON AGBA ODALE iLE YORUBA
God bless you Baba shobuyi, you will live Long sir❤
Kaabo Baba Arole 10 10. Ota o nii riyin mu ooo
Orile-ede Yoruba, ebute Ayo.
Oluwa Adurotie ; Oluwa a di e mu. Gbogbo Adura Evangelist Michael ni orile ede Isreal a wa si imuse lori re. Ko si oun buruku ti yo sele si e ni oruko Jesu. Ma Ranti ni Igba gbogbo pe baba 1010 ko sun rara, nitoripe eni iriju Olorun ni
Baba Shogbuyi. E SE again Olorun atun maran yin lowo Ni gbogbo ona.
Bi esenfe Ni Olorun Olodumare yio ma fun yin Ni Oruko Jesu amiin.
Mummy Tella Abimbola I Thank Almighty father for your life, Grace, Grace ,Grace is your Strength and your Story INJMN Ameeen. 🙏
Arole ,iwa ni bi iwe Yoruba ti so wipe toju iwa re ore mi. May the Lord God Almighty bless Mr Sogbuyi mightily.
Yoruba nation must surely conquered by the power in the mighty name of Jesus Christ.
God bless
Thank you Baba, God Almighty will reward you abundantly sir IJN.
amen don't forget to thank mr shobuyi thst help us to continue seeing our brother arole .
Thanks so very much Baba Shobuyi. Thank u sir
may God bless mr shobuyi, more blessing ijn , eseun pupo ibi ti eti mu owo phone ti e bawa ra fun arole baba 10 10 jp obalola , olorun afi opo ropo , may thy lord continue to bless ur work ijn ,
Thanks sir, more blessing......
ASE ASE ASE ASE ASE ASE Edunmare
Arole Baba 10 10 a dara fun e tomotomo. May God bless you mightily.
Go straight to the point
❤thank baba shobuyi baba 10 10 arole won se ra won ni yoruba nation lo ma bori won
AMIN AMIN AMIN OLOHUN OOO
ESEHU SIR OOO
Ekabo oooo aseye ni alakan nse epo aseye lama se oooooo
You are welcome. Ase ye lema se o Amin 🎉
Awon baba radarada brainless leaders and elders shame on them all and all their generations
ELEDUMARE A BAWA DUPE LOWO YIN BABA SUBUYI.
E KONI MO INIRA LAYE .
You are welcome my brother.
and pls thanks mr shobuyi that help us bcos of another time , one love ❤
God bless baba Arole baba 10 10 God bless mr shobuyi
APOTI ERI APOTI ibi Fe KO Ogunn ja Ile Yoruba agitators .
Adupe lowo baba tora phone (Showuyi) fun Omo baba 10 10. Owo yon onikan isale apo.
❤❤❤
ALLAHU AKIBAR KEEEBIRAAA
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
O dàbí ẹnipe ọrọ kìí tètè yé àwa ọmọ Yorùbá. Tinubu ko so fún ẹnikẹ́ni télè pé òun fẹ wá gba ọmọ Yorùbá là. O so pé ibiti Buhari fi ìjọba ti sí ní oun ti máa túnbọ̀ tẹ síwájú sí. Ṣe Tinubu ko sí láyé ni ìjọba Buhari ti àwọn Fúlàní npa kúkúrú pa gigun ní ilẹ Yorùbá ti kò sòrò. Àwa ni kí a mọ̀ bi a ṣe máa yo ara wa kúrò l'oko ẹru wọn.
Alausa
What is the matter with this afenifebi wonyi se won ni omo ni won ronu atunbotan
Ekaaboo emaberu
Beeni ni agbara Edumare
Adupe o,Olorun a sanyin esan re o(Ami).
A o tile need aare Ona kakanfo mo
Otito
Ojometa oluwa mawapelue
Ejowo mosofun baba ekiti pe kiwonfun mi mi number oloye Sunday igboho mofeso orokan funwon
.
A dupe lowo Baba shobuyi
Yoruba nation is a sure banker whether they like it or not. Afenifere is doing what they are doing out of envy and jealousy. Infact, they did not support president Tinubu election, and this was done also out of jealousy and envy. They have betrayed Baba Awolowo and yorubas.
You are fighting for yourown interest.
Ekaaboo emaberu