EARLY MORNING PROPHECY || LIVE || PROPHET SAMUEL ADEBAYO OJO (BABA AUTHORITY).

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 23. 06. 2024
  • EARLY MORNING PROPHECY || LIVE || PROPHET SAMUEL ADEBAYO OJO (BABA AUTHORITY).

Komentáře • 19

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Gbogbo ide amunileru lara mi ati awon omo ologo mi, ni oruko Jeeeesu, ko maa ja, gbogbo ide ojukan lara mi ati awon omo mi, ko maa ja, Jesu lo pase bee, iwo ide amunileru lese, lese awon omo mi, maa ja, ide maa ja loni loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Maa yee tomotomo mi, nitori angeli kii ku lorun, emi ati awon omo mi yoo ye dandan loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Ni oruko Jesu, oruko mi gba itusile, oruke awon omo mi gba itusile, aye mi, aye awon omo mi gba itusile loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Okun airi ti a fi de mi de ogo mi, ti a fi de awon omo mi togotogo, Oluwa ja laaro yi, gbogbo ide lara mi ati awon omo mi maa ja loruko Jesu, ide maa ja

  • @maryoluranti4652
    @maryoluranti4652 Před měsícem

    Amin Amin Amin Loruko JESU

  • @maryoluranti4652
    @maryoluranti4652 Před měsícem

    Mo jade kiro ninu Yara Iku, mowo Yara iye,iye ni temi ati ti gbogbo Ile mi loruko jesu.Eni to ba perimi nibi back to sender,Eni ton fiku wami kiri kofi emi e di loruko jesu.iye ni temi mogba iyeeeeeeeeee loruko jesu.

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Ni oruko Jesu, lori awon omo mi, emi o daamu mo, lori oro ise omo mi, nibi ti won lowolowo, angeli aanu koja lo sibe ki o lo se ilaja laarin oga ati omo ise, aanu lo fohun fun omo mi, iyanu yi ka loruko Jesu, gba kokoro okan oga fun loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Emi iku lara mi, ati awon omo mi jade - amin amin amin loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Amin Jeeesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Oluwa ki o to pe 24 hours ran iranlowo ojiji si mi, ran si awon omo mi loruko Jesu, ko to pe 24hours ran iranlowo ojiji re si awon omo mi, ran iranlowo re si ile aye wa, iranlowo igbedide nitosi ati nibi to jina Oluwa ran si mi ati awon omo mi loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Lori Authority lori awon omo mi, gba gbogbo ogo, lo gbogbo agbara lati so irin ajo won di irorun, gbogbo ogun to n dode won, Olorun Authority ba mi gbe won mi loruko Jesu, je ki aye won gba itura ati isinmi, je ki won ri aanu ati ojurere gba lowo oga ise loruko Jesu

  • @codedguy8126
    @codedguy8126 Před měsícem

    You Amin loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Amin Jesu

  • @taiwoadeyemo6646
    @taiwoadeyemo6646 Před měsícem +1

    Mo Jade kuro ni iyara iku ,mo wo iyara iye lo pelu awon omo mi at'aya mi

  • @funkemary1136
    @funkemary1136 Před měsícem

    Psalm 27, 102, 23 honey, water and oil. Ok sir.

  • @AdenikeOlagunjoye
    @AdenikeOlagunjoye Před měsícem

    Baba Authority please visit us in Badagry axis sir from Oladunjoye Adenike Olufunke

  • @taiwoadeyemo6646
    @taiwoadeyemo6646 Před měsícem

    Emi iku Jade Lara mi ati awon omo mi pelu iyawo

  • @ibraheemtemitopemosunmola4096

    Well done sir! Please Sir, how can I contact you directly sir.