OGBOJU ODE|| Wọn ti ran Sango si mi ri bíi ẹẹmẹta sugbọn Ògún ko jẹ ki o le bami ja.

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 30. 07. 2023
  • #ewaede #asa #cute #edeyoruba #kingsolomon #papaya #tundeednut #isese

Komentáře • 77

  • @sukuratibrahim7414
    @sukuratibrahim7414 Před 11 měsíci +2

    Nice one sir

  • @ayanlekeayanniyi6705
    @ayanlekeayanniyi6705 Před 11 měsíci +2

    Very useful program please keep it up sir

  • @ajeyemimayokun267
    @ajeyemimayokun267 Před 11 měsíci +2

    Wow, wow, I really enjoyed this

  • @adedejiademola3965
    @adedejiademola3965 Před 11 měsíci +2

    Oyeolohun I owed you money don't worry please continue like this💕

  • @ogunlekebosede6372
    @ogunlekebosede6372 Před 11 měsíci +2

    May God bless your work sir

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️

  • @olaifamoruf642
    @olaifamoruf642 Před 11 měsíci +2

    Ogun amadowo fun yin ooo

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ

  • @babaarifokanble2372
    @babaarifokanble2372 Před 11 měsíci +2

    . Kabiesi Bàbá " Kí Èmí olá ó gùn Bàbá.

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Ọ̀rẹ́ mi bóo ni ooo

    • @babaarifokanble2372
      @babaarifokanble2372 Před 11 měsíci

      @@OYEOLOHUN_TV
      Ayò niifah " Akú Aféré yìí, Alaafia Ara wa yio lekun MBE.

  • @tosindada965
    @tosindada965 Před 11 měsíci +2

    E ku ise takun-takun... KO ni buru fun yin laelae

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ayé ti yín náà kòní bàjẹ́ lágbára Olódùmarè ✌️

  • @tawakalituabeke9920
    @tawakalituabeke9920 Před 11 měsíci +2

    Weldone sir

  • @feliciaadejoke
    @feliciaadejoke Před 11 měsíci +2

    Esun baba agbayin adaleo

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ma✌️

  • @AdekannbiAjagbe-gj3et
    @AdekannbiAjagbe-gj3et Před měsícem

    Hummm, I really enjoy your program sir ❤️

  • @AyindeAishat-dm7hc
    @AyindeAishat-dm7hc Před 11 měsíci +2

    Olorun Koni pada leuin yin

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, atẹyin naa✌️

  • @angelabailey8748
    @angelabailey8748 Před 10 měsíci +2

    Mo ti gbo pe ode ile yoruba wo, ni o
    Pa zebra ri

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 9 měsíci

      Zebra báwo? Kosi Zebra nilẹ yoruba

  • @sanusikazeem9098
    @sanusikazeem9098 Před 11 měsíci +1

    ❤❤❤❤❤❤

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 10 měsíci

      Ẹ seun, ẹran ìfẹ́ ara ti yín náà kòní di ẹran ìkórira✌️

  • @AdeniyiOlu
    @AdeniyiOlu Před 25 dny

    Olotu am so impressed with the way u do ur program am really in love to watch oyeolohun tv ❤

  • @daudaalao1337
    @daudaalao1337 Před 11 měsíci +2

    Very good of you my brother much love 💕

  • @abassireakari2715
    @abassireakari2715 Před 11 měsíci +2

    Hummm very good program 👍

  • @abubakiriismail605
    @abubakiriismail605 Před 11 měsíci +2

    Kudos to you my brother

  • @abdullahisade5127
    @abdullahisade5127 Před 11 měsíci +2

    Weldone My brother

  • @AlabiAdekunle-jm5ln
    @AlabiAdekunle-jm5ln Před 11 měsíci +2

    Olorun a ma bayin se sir

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci +1

      Àmín o, Ẹ seun púpọ̀ ✌️❤️💯

  • @SegunKayode-uy5yn
    @SegunKayode-uy5yn Před 11 měsíci +2

    Well done as usual sir, thanks for holding up our heritage.

  • @TIAMIYUMUSBAU-ic1zz
    @TIAMIYUMUSBAU-ic1zz Před 10 měsíci +2

    A ni shi se o. Iwaju la o maa lo

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 10 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️

  • @rahmonzainab1661
    @rahmonzainab1661 Před 11 měsíci +2

    Hnnnn this is the third time timo ntun program yi wo konibaje fun yin

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️

  • @mujidatuadunni7228
    @mujidatuadunni7228 Před 11 měsíci +2

    Oyeolohun you are doing great job keep it up my brother

  • @olawaleakanbi3099
    @olawaleakanbi3099 Před 11 měsíci +2

    Oye Ọlọ́run tv eku ọjọ́ mẹta ooo

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Ọjọ́ kan pẹ̀lú Ẹ̀gbọ́n mi dada, Ẹ seun sir✌️

  • @senghorplc1450
    @senghorplc1450 Před 11 měsíci +2

    Ejowo kini itumo "ero iroko?"

  • @ogunsijijoseph802
    @ogunsijijoseph802 Před 11 měsíci +2

    Eku Eto sir amajuyin se o

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ✌️

  • @OlayinkaAjasa-iy3mw
    @OlayinkaAjasa-iy3mw Před 11 měsíci +2

    Mogbadun program yin gon ni

  • @gofarazeez7348
    @gofarazeez7348 Před 11 měsíci +2

    Iso olorun adaju Lori yin sir eku ojo meta

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, ọjọ́ kan pẹ̀lú sir ✌️

  • @maryme1519
    @maryme1519 Před 11 měsíci +2

    Oto ojo meta Oyeolohun broda mi❤

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Bẹẹni sir, kí ó lè da náà ni gbogbo ẹ, Ẹ seun ✌️

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Ẹ seun Ẹ̀gbọ́n mi, Olódùmarè kòní fi yín sílẹ̀ ✌️

  • @alaodauda1439
    @alaodauda1439 Před 11 měsíci +2

    Keep it up My brother we dey enjoying your program

  • @anthonysmith3720
    @anthonysmith3720 Před 11 měsíci +2

    Our beautiful program is back.. No matter how Nigeria situation is.. You and your crew will not experience hardship and an accident

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci +1

      Àmín àṣẹ Èdùmàrè, bí ẹ ṣe fẹ́ kí ó rí fún wa ní ti dáadáa, ó ma rí bẹ̀ fún ẹ̀yin náà. Ẹ seun púpọ̀ ✌️

  • @christopherojolola953
    @christopherojolola953 Před 11 měsíci +2

    Always my respect baba mi

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Ẹ seun my one and only brother, boss, manager, helper, my friend, my partner, may God bless you forever

  • @bisayokakawa4760
    @bisayokakawa4760 Před 11 měsíci +2

    Ejowo nibo Ilu Ede wa?

  • @ogunlekemayowa9057
    @ogunlekemayowa9057 Před 11 měsíci +2

    Eseun fun awon ise gidi te nse ejor nibo lo nje tede and sewon ma nta ede ni

    • @feliciaadejoke
      @feliciaadejoke Před 11 měsíci +1

      Tede wani ipinle oyo ni atisbo local government ni oke ogun won ta ede nibe o

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Àwa náà kọ̀ọ́ Olódùmarè ni, Bí o ṣe jẹ́ gan ni Ìyáàfin Felicia wí hun✌️

  • @adewilliams8
    @adewilliams8 Před 11 měsíci +2

    Correction, it should be Oye-Olorun and not Oyeolohun. Please don't bastardise Yoruba language.

    • @OYEOLOHUN_TV
      @OYEOLOHUN_TV  Před 11 měsíci

      Ọlọ́run gan-an tí ẹ ń sọ kò bójú mu tó. Olódùmarè ló yẹ kí á ma wí. Ṣùgbọ́n kò sí àsìkò fún gbogbo ìwọ̀nyẹn báyìí, Ẹ seun

  • @haqqiganiyy4706
    @haqqiganiyy4706 Před 11 měsíci +2

    May God bless your work sir