![OYEOLOHUN TV](/img/default-banner.jpg)
- 106
- 616 214
OYEOLOHUN TV
Nigeria
Registrace 22. 04. 2020
Gbígbé àṣà àti ìṣe pẹ̀lú èdè Yorùbá lárugẹ ló jẹ wá lógún.
Ẹ lè kàn sí wa lórí:
*Instagram: oyeolohun_tv
*Tiktok: OYEOLOHUN_TV
*Facebook: Oyeolohun88
Gmail: oyeolohunnaa@gmail.com
Ẹ seun tí ẹ̀ ńtẹ́tí gbọ́ wa, ẹ le pè wá sí ẹ̀rọ ìbára ẹni sọ̀rọ̀ yìí 08069316812. Bí ẹ bá ní ohun láti bá wa sọ. Ire ni tiwa tẹ̀yin lọ́jọ́ gbogbo. Ooodabọọọ. 🙏
Ẹ lè kàn sí wa lórí:
*Instagram: oyeolohun_tv
*Tiktok: OYEOLOHUN_TV
*Facebook: Oyeolohun88
Gmail: oyeolohunnaa@gmail.com
Ẹ seun tí ẹ̀ ńtẹ́tí gbọ́ wa, ẹ le pè wá sí ẹ̀rọ ìbára ẹni sọ̀rọ̀ yìí 08069316812. Bí ẹ bá ní ohun láti bá wa sọ. Ire ni tiwa tẹ̀yin lọ́jọ́ gbogbo. Ooodabọọọ. 🙏
OGBOJU ODE || Gbogbo Awon Alujonnu, Ebora, Kosi eyi tole fi owo kan ise ti moba se.
#folklore #ogun #asa #africa #asayoruba #love #animals #edeyorubarewa #funny #challenge #hunter #ifa
zhlédnutí: 1 590
Video
OGBOJU ODE || Ojo ti mi o le gbagbe lojo ti mo to ipa ese Abami ekulu titi mofi sonu sinu igbo.
zhlédnutí 3,6KPřed 14 dny
#asayoruba #folklore #ogun #edeyorubarewa #africa #africa #animals #asa #asa #folklore #animals #love #culture #culture #funny
AISUN ODUN EGUNGUN 2024 T'ILU TEDE.
zhlédnutí 345Před 28 dny
#edeyorubarewa #folklore #africa #asa #animals #asayoruba #love #animals #love #asayoruba #culture #funny #ifa
OGBOJU ODE || Odo ti eja inu re kii Jina ti won ba pa, ti won se e nilu Ago Amodu.
zhlédnutí 3,4KPřed měsícem
#edeyorubarewa #africa #folklore #asa #animals #asayoruba #love #love #culture #funny #ifa #ogboninunogboninuntv
OGBOJU ODE || Mo Pade Alujonnu, O yira pada di Obinrin to ro aso dudu ati funfun ninu Aginju.
zhlédnutí 6KPřed měsícem
#folklore #asa #africa #asayoruba #funny #edeyorubarewa #culture #edeyorubarewa #ifa #ogun #viralvideo #share
OGBOJU ODE || Ki nto gba ise tabi Ki won to gbe eniyan de odo mi, won a ti so iru isoro eni be funmi
zhlédnutí 4,7KPřed měsícem
#africa #asa #asayoruba #culture #edeyorubarewa #ifa #ogun #viralvideo #yoruba #ogboninunchannel
OGBOJU ODE || Mo Pade Eranko Agbonrin to yirapada di Eniyan, O toro omi lowo mi...
zhlédnutí 41KPřed 2 měsíci
#asa #yoruba #asayoruba #africa #ogun #edeyorubarewa #culture #ifa #iseyoruba #viralvideo
OGBOJU ODE || Alujonnu, Ebora ko je nnkan kan si emi, Alujonnu tan ina ehin si mi, Mo yin ibon si...
zhlédnutí 4,1KPřed 4 měsíci
#asa #asayoruba #edeyorubarewa #ifa #papaya #tundeednut #yoruba #youtubeshorts #oweileyoruba
OGBOJU ODE || Kosi Osanyin kankan Laye Mo, Iro loku, Aanu Ile yoruba se mi nitori enu loku...
zhlédnutí 6KPřed 4 měsíci
#asa #asayoruba #edeyorubarewa #ifa #papaya #tundeednut #yoruba #youtubeshorts #owenwilson
OGBOJU ODE || Emi ati Awon emi Airi, Ebora, jo ma nsere labe igi lapalapa lati igba kekere mi ni...
zhlédnutí 9KPřed 4 měsíci
#youtubeshorts #yoruba #asayoruba #asa #edeyorubarewa #tundeednut #papaya #ifa
OGBOJU ODE || Eniti Koni oogun, ti ko mo nnkan kan ko le losi inu aginju ti ebora, Efon, Ajanaku wa.
zhlédnutí 6KPřed 6 měsíci
#papaya #asa #ewaede #cute #edeyoruba #edeyoruba #isese #tundeednut #yoruba
OGBOJU ODE || Alujonnu Ebora tan ina, o nto mi bo, O Niki nkuro loju ona awon...
zhlédnutí 6KPřed 7 měsíci
#papaya #asa #ewaede #cute #edeyoruba #isese #kingsolomon #obasolomoni #tundeednut #yoruba
OGBOJU ODE || Kosi Isoro Ti Ifa Kole Yanju Ti Babalawo Ba Gbo Ifa Dada Ti Kosi Fi Iro kun...
zhlédnutí 2,3KPřed 8 měsíci
#asa #asa #cute #edeyoruba #ewaede #ewaede #isese #kingsolomon #obasolomoni #papaya #papaya #papaya #tundeednut #yoruba
OGBOJU ODE || Won Ko i ti Bimi Saye Ti Won Ti Sope Omo To Nbe Ninu Iya Mi Wipe Ifa Ni...
zhlédnutí 4,7KPřed 8 měsíci
#asa #cute #edeyoruba #ewaede #isese #kingsolomon #obasolomoni #papaya #tundeednut #yoruba
OGBOJU ỌDẸ || Ẹbọra Alujọnnu wa bami ninu oko, o sọ asiri funmi, A sidi ọrẹ di oni oloni...
zhlédnutí 13KPřed 9 měsíci
#asa #cute #edeyoruba #ewaede #isese #kingsolomon #papaya #tundeednut #obasolomoni #yoruba
OGBOJU ODE || Aja gbemi lo fun ojo meje, Mi o mo bi Aye ni mowa bi orun...
zhlédnutí 6KPřed 9 měsíci
OGBOJU ODE || Aja gbemi lo fun ojo meje, Mi o mo bi Aye ni mowa bi orun...
OGBOJU ODE|| Awọn Iwin ti mo pa to mẹẹdogun, ati ọ̀run ni moti gbe agbára mi wa...
zhlédnutí 7KPřed 9 měsíci
OGBOJU ODE|| Awọn Iwin ti mo pa to mẹẹdogun, ati ọ̀run ni moti gbe agbára mi wa...
OGBOJU ỌDẸ || Baba mi pa Iwin Àlùjọ̀ǹnú, O gbe orí rẹ wasi ile, O nbẹ ninu iyara...
zhlédnutí 25KPřed 10 měsíci
OGBOJU ỌDẸ || Baba mi pa Iwin Àlùjọ̀ǹnú, O gbe orí rẹ wasi ile, O nbẹ ninu iyara...
OGBOJU ODE|| Onílù oba yirapada di okuta, ọba yirapada di olufa, ó fà wọnú igbó lọ.
zhlédnutí 11KPřed 11 měsíci
OGBOJU ODE|| Onílù oba yirapada di okuta, ọba yirapada di olufa, ó fà wọnú igbó lọ.
From Car Hire and Hire to Driving Toyota Siena. Glory Be To God Almighty and You all my supporters.
zhlédnutí 891Před 11 měsíci
From Car Hire and Hire to Driving Toyota Siena. Glory Be To God Almighty and You all my supporters.
OGBOJU ODE|| Wọn ti ran Sango si mi ri bíi ẹẹmẹta sugbọn Ògún ko jẹ ki o le bami ja.
zhlédnutí 14KPřed 11 měsíci
OGBOJU ODE|| Wọn ti ran Sango si mi ri bíi ẹẹmẹta sugbọn Ògún ko jẹ ki o le bami ja.
OGBOJU ỌDẸ NINU || Ti ìdè kò bá já kúrò Lára, Bi eniyan ba nlo Oogun, oogun yẹn kòní sisẹ lára rẹ.
zhlédnutí 4,8KPřed rokem
OGBOJU ỌDẸ NINU || Ti ìdè kò bá já kúrò Lára, Bi eniyan ba nlo Oogun, oogun yẹn kòní sisẹ lára rẹ.
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO || Ẹbọra Gbe mi Lati inu iyara wasi inu ọgbà, mo sun ti olufa
zhlédnutí 12KPřed rokem
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO || Ẹbọra Gbe mi Lati inu iyara wasi inu ọgbà, mo sun ti olufa
ORÚKỌ ÀWỌN TÓ KÚN WA LỌ́WỌ́ LÓRÍ ỌKỌ̀ TÍ A FẸ́ RÀ PẸ̀LÚ IYE TÍ OWÓ DÌ.
zhlédnutí 655Před rokem
ORÚKỌ ÀWỌN TÓ KÚN WA LỌ́WỌ́ LÓRÍ ỌKỌ̀ TÍ A FẸ́ RÀ PẸ̀LÚ IYE TÍ OWÓ DÌ.
OGBOJU ODE NINU IGBO || Idi ti a ko fi gbe fọ́nrán ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú àwọn ọdẹ síta dada mọ́.
zhlédnutí 2,7KPřed rokem
OGBOJU ODE NINU IGBO || Idi ti a ko fi gbe fọ́nrán ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú àwọn ọdẹ síta dada mọ́.
OGBOJU ODE NINU IGBO || Mo yin ibọn pa Iwin to nfa ìbọn mọmi lọwọ Latẹyin.
zhlédnutí 7KPřed rokem
OGBOJU ODE NINU IGBO || Mo yin ibọn pa Iwin to nfa ìbọn mọmi lọwọ Latẹyin.
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO || A pade Ẹbọra to nfi ori rin bọwa, o fẹ bawa ja, ó yira pada di Igala, A pa..
zhlédnutí 12KPřed rokem
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO || A pade Ẹbọra to nfi ori rin bọwa, o fẹ bawa ja, ó yira pada di Igala, A pa..
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO || Moba egbere ja, mo gba ẹni egbere, melo la fẹ ka...
zhlédnutí 13KPřed rokem
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO || Moba egbere ja, mo gba ẹni egbere, melo la fẹ ka...
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO; Ọjọ ti ejo we mọmi lọrun nibi moti ntọ igala lọ.
zhlédnutí 9KPřed rokem
OGBOJU ỌDẸ NINU IGBO; Ọjọ ti ejo we mọmi lọrun nibi moti ntọ igala lọ.
You good my friend don't worry 🎉
Wow, there's nothing more understatement is you are good on this way of an interview
Eku eto sir olorun ama funyin se
Kudos to you sir 🎉
Nice job sir
❤❤❤
Weldone sir may God continue to be moving you forward
Very educative program weldone my dear bro❤
Phone number .
OyeOlorun e se gan ni .
Omoh he go far ooo
Who has been to Baba s place and can testify
❤❤❤❤❤❤
❤❤❤
Thanks ✌️
Eledumarè yiò bàwà dà emì babà sì fun nù wà
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ✌️
I love your program, mostly because you always show us the pictures of the animals 😊
This probably the best episode ever. Thank you once again....
Thanks sir, ojoojumọ la o ma titun si✌️
Thank you for the episode... Nn'le Omo Agoro
Ẹ seun púpọ̀, Aburú ó kéré, ó tóbi kòní wọlé tọ yín ✌️
Nice one sir Baba mi
Ẹ seun sir Ẹ̀gbọ́n mi dada, ọ̀dá itọ́ kìí dá ahọ́n, ọ̀dá ohun rere kòní da yín ✌️
Nice one sir Hi
Ẹ seun sir Ẹ̀gbọ́n mi ✌️
Moferan asa ile Yoruba pupoju Much 🖤 my brother 🙏🏼
Ẹ seun púpọ̀ sir, Kòní bàjẹ́ fun yín ✌️
Weldone my brother Oyeolohun
Ẹ seun Ìyáàfin Kosenat, a kìí wá irú tì lọ́bẹ̀, n kò ní fi yín sàwátì✌️
Weldone sir, I really enjoy the way you are speaking yoruba language
Thanks a million
Thanks ✌️
I love your program sir ❤️
We love you too Alhaja ✌️
Koni suyin koni reyin lagbara olorun ❤
Àṣẹ, Àsetì kìí bá ọjọ́ kí ọjọ́ kó má yọ, àsetì kòní ba yín ✌️
Thanks
You welcome ✌️
Very educative program weldone sir
Thanks sir ✌️
You are doing well sir
Thanks and you too sir
Kudos to you my brother plz I have a question for baba
No problem, I will send his phone number to you on your WhatsApp ✌️
Very educative program weldone my brother but plz let it be once or twice in a week sir
Thanks for the love sir, we will try our best, may God help us ✌️
E seun atokun eto opolopo ikan tikoyemi tele loti yemi latigba timo tu ntele yiin lori eto yi
Olódùmarè ni àwa náà kọọ́, ọpọlọ gbogbo wa kòní dàrú ✌️
Weldone sir ❤
Thanks sir ✌️
Eku igbiyanju sir olorun a jeki osese fun yin
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀, kòní bàjẹ́ fún ẹ̀yin náà lágbára Olódùmarè ✌️
Weldone sir I always enjoy your program sir may God bless your hustle
Amen ooo, Thanks for the love, ojoojumọ lọrọ ikoro ma nba ewuro, ojoojumọ lo nburu fún àgbò, kòní burú fun yín ✌️
First to comment
Thanks My brother for the love since day one ✌️
Thank you my brother, really appreciate your efforts
Do we have lions, hyena in tropical rain forest 😅
What a good lesson and illustration, baba may God keep you, I wish to know you.
This guys think we are fools. They cook up mystery stories to decieve the gullible. With the kind of spiritual power they claim, yet ordinary fulani boy will kill them anyhow like chicken. But they will come out to us and make mouth. Abeg park well
Thanks god bless you Pls give me baba number and address to locate him sir his a grate and wonderful man
I
Baba wan dey turn to lion 🤣🤣🤣🤣🤣 Power choke for here
Please can i have baba number
Iluwo ni babawa,efunwa ni no baba
Konibajeo Lola awon eni olohun
Emi lu Daiko ninu Oshodi ri ooo. Ojo meje ni mo lo ni Oshodi.. But on a serious note... This old man is very truthful. Much respect
Amin ati gbogbowa ❤
Eku eto atokun,igba keji ti ma wo iforowero pelu Baba wa niyi,,inu mi osi dun lati yoo ju si Baba fun adura ni saki.
Atokun ekuse takuntakun..
The flute sounds like " Praising the lord alwaaaays"😂