ITAN OGUN OTEFON 11

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 7. 09. 2024
  • Fún alaye àti ibere nípa Itan Yoruba ẹ kan si wa Aare Laji Abbas +2348023687432

Komentáře • 14

  • @thickbarbieskitchen1159

    Eku ise takuntakun olukowa

  • @ASAOOTU
    @ASAOOTU Před měsícem +2

    Ẹṣe Laji Abass fun awon itan pàtàkì yìí, Ẹkọ ti mo kọ nínú gbogbo itan yii ni wipe, nkán ti wọ fun Yorùbá lati ilẹ wa. Iwa ọdàlẹ ati asilo àgbàrá lo fa ìṣòro fun Yorùbá. Ẹ jọwọ ẹ ṣe eto fun itan Ìjèṣà. Adupẹ o

  • @user-rn8pw6vs8t
    @user-rn8pw6vs8t Před měsícem +1

    Ajinde ara a ma jẹ o. Ọrọ pada kàn Agọ-Ọja nibi ti ija ilẹ ti nlọ lọwọ laarin awọn Ọyọ ati awọn ara Agọ. Bóya ayipada orúkọ ba ba wa, iye wa ma ṣi.

  • @isholasulaimano.7903
    @isholasulaimano.7903 Před měsícem +3

    Baba eku ise ilu konibaje fun yin

  • @user-nj3qx4xh2d
    @user-nj3qx4xh2d Před měsícem +2

    IGBOHO OOOSHA MY HERO ♥️

  • @loantha2996
    @loantha2996 Před měsícem +2

    Alale lo ma mu gbogbo awon odale Yoruba

  • @adeoyeesther6711
    @adeoyeesther6711 Před měsícem +2

    Olóyè Ààre Òpìtàn...... Ẹku isẹ ìlú, ẹ ó jèrè ẹ ó f'eree jeko o

  • @Adekola-gu1fl
    @Adekola-gu1fl Před měsícem

    ❤❤❤❤❤❤❤❤❤

  • @AdesolaOladeji-d8m
    @AdesolaOladeji-d8m Před měsícem +1

    Eku eto sir eku ise ilu ❤ emin yin agun

  • @akintundeokelade2563
    @akintundeokelade2563 Před měsícem +1

    Good job. Thank you very much.

  • @damilolaolayiwola611
    @damilolaolayiwola611 Před měsícem

    Can you please tell us how we come by the name 'Oyo' ?

  • @kazeemogundeji7925
    @kazeemogundeji7925 Před měsícem +1

    Eku ise opolo.... AKASOLORIIRO

  • @loantha2996
    @loantha2996 Před měsícem

    Was Ogedengbe around during Pole

  • @davidebenezer6217
    @davidebenezer6217 Před měsícem

    ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤