Ìdó Gbágùrá àti Ọ̀jọ́ọ̀ Gbágùrá wà ní Abẹ́òkúta.. Bákan náà ni Ìbàdàn Gbágùrá,,, Mọ́kọ́la, Idi-Apẹ́, Ijoko, Ìjàyè Kunrunmi àti Ìjàyè Kúkúdi wà ní Abẹ́òkúta.. Bẹ́ẹ̀ni.. Ojú kanna ni Ìjàyè wá. Ibe na ni First Baptist Church Abeokúta wà. Chief Bọ̀dé Mustapha tí wọ́n jẹ́ Balogun Ìbàdàn Gbágùrá ni Osí Ẹ̀gbaland lásìkò yìí..
Thank you Are Laji Abass for all our own history you're telling us Omo-Oko yoruba tooto. It's high time we stop the Fulanis from suppressing us in yoruba land. Fulani most leave our land, Our yoruba land start from the End of Jebba to the Atlantic, which Ilorin is inside it.Our Ilorin Afonja. By the grace of God almighty when will get our yoruba Nation,all the nonsense will stop, enough is enough!
Igbekoyi is forest refuses this one. Ki se igbe ti a nya lati Ara wa. Igbe ni Yoruba tumo Di Igbo kijikiji Idi re ti awon ode ba lo si igbo lati pa eran won so wipe a nlo degbe. Are opitan O ku ohun.
Ebenezer Obey ni: "To bá jẹ́ ti kà náwó wọn kìí rójú owó.. Ká kọ́lé ká ra mọ́tò, Ìjẹ̀ṣà lo nìyẹn. Ẹ wá wo àrà tí Ìjẹ̀ṣà fowó dá, Èdùmàrè má gba sáà náà lọwọ́ wọn... Ọmọ oloni wọwọ tíì wọ,, Bẹ́ẹ̀ni,,, ọmọ olobi wọ̀wọ̀ tíì wọ̀wọ̀,, Bẹ́ẹ̀ni.. Èyí tó bá fẹ́ ni a wọ̀ sapo ẹni, Èyí tí ó fẹ́ ni a wọ̀ sínú igbó, Bẹ́ẹ̀ni.. Ẹranko búburú a máa roun mú jẹ, bẹẹni... Ọ̀bun wo ọjà a pa sisio wọ ọjà, "" Bẹ́ẹ̀ni.. ".. Bo tiẹ̀ jẹ́ pé wọn ò ná owó fún Ààrẹ Òpìtàn.
U are blessed Aree Laji Abass
Haaa baba yi gan ni itan. Oopo bi yeepe
Laji ẹ ma gbomi s'ẹgbẹ. Ẹkuṣẹ takuntakun.
Congratulations Aare OPITAN of the World.. on your new Awards..
Alhaji, you are very good Sir.
God bless you.
Njotan Eko 😂...
Sir, I love your programme. Though I have reservations on your history of Ilorin.
Respect 🫡 tegan loku you’re the real Aare Opitan may your be long
I'm really impressed hearing this great history from you sir. Ọlọrun eledumare a jẹ ki ẹ pẹ fun wa o. Ilẹ ootu- ojiire ko ni daru o. More wisdom sir❤
Lhaji abass Emin yin agun❤
Aree ounpitan Ile Yorubaaaaa
Epe fun wa oooo
Ìdó Gbágùrá àti Ọ̀jọ́ọ̀ Gbágùrá wà ní Abẹ́òkúta.. Bákan náà ni Ìbàdàn Gbágùrá,,, Mọ́kọ́la, Idi-Apẹ́, Ijoko, Ìjàyè Kunrunmi àti Ìjàyè Kúkúdi wà ní Abẹ́òkúta.. Bẹ́ẹ̀ni.. Ojú kanna ni Ìjàyè wá. Ibe na ni First Baptist Church Abeokúta wà. Chief Bọ̀dé Mustapha tí wọ́n jẹ́ Balogun Ìbàdàn Gbágùrá ni Osí Ẹ̀gbaland lásìkò yìí..
Thank you Are Laji Abass for all our own history you're telling us Omo-Oko yoruba tooto.
It's high time we stop the Fulanis from suppressing us in yoruba land. Fulani most leave our land, Our yoruba land start from the End of Jebba to the Atlantic, which Ilorin is inside it.Our Ilorin Afonja.
By the grace of God almighty when will get our yoruba Nation,all the nonsense will stop, enough is enough!
Ajitoni ma ji tola ORUKO abiku nii
Well don baba
Are opitan.... kudos (gbe fun)
Adaku moko osan oruko abiku ni 😅
Igbekoyi is forest refuses this one. Ki se igbe ti a nya lati Ara wa. Igbe ni Yoruba tumo Di Igbo kijikiji Idi re ti awon ode ba lo si igbo lati pa eran won so wipe a nlo degbe. Are opitan O ku ohun.
Oluko agba eku eto yoruba nation no going back
I hope you can delve into the British war against Ijebu as well, the Battle of Imagbon.
❤❤❤❤❤❤❤❤❤Aare, Eku Bibiire, Kii E Pe Fun Wa🙏🏽🙏🏽🙏🏽
Good job Aare Opitan
❤❤❤❤❤❤❤❤❤, more blessings sir
Kumuyilo
Saw❤
Ebenezer Obey ni: "To bá jẹ́ ti kà náwó wọn kìí rójú owó.. Ká kọ́lé ká ra mọ́tò, Ìjẹ̀ṣà lo nìyẹn. Ẹ wá wo àrà tí Ìjẹ̀ṣà fowó dá, Èdùmàrè má gba sáà náà lọwọ́ wọn... Ọmọ oloni wọwọ tíì wọ,, Bẹ́ẹ̀ni,,, ọmọ olobi wọ̀wọ̀ tíì wọ̀wọ̀,, Bẹ́ẹ̀ni.. Èyí tó bá fẹ́ ni a wọ̀ sapo ẹni, Èyí tí ó fẹ́ ni a wọ̀ sínú igbó, Bẹ́ẹ̀ni.. Ẹranko búburú a máa roun mú jẹ, bẹẹni... Ọ̀bun wo ọjà a pa sisio wọ ọjà, "" Bẹ́ẹ̀ni.. ".. Bo tiẹ̀ jẹ́ pé wọn ò ná owó fún Ààrẹ Òpìtàn.
Aye laagbe kasi mawo aja
Well don baba