Ekuse takutaku Oluwa Olodumare aranwalowo Amin o. Yoruba Nation no going back, Yoruba Nation now now now. God bless all Agitators for Yoruba Nation. God bless Prof Akintoye Adebanji, Chief Sunday Adeyemo Igboho Oosa and all people of Yoruba Land. Orilede Yoruba la fe ni kia kia kia. Ase Eledumare. God bless all people in house.
O maa pa Gani Adams lori adabi to ba ti je pe oun lo da EGBE O P C sile .laipe laijina lagbara Alawura alale Ooodua maa ye Gani Adams lese gbogbo awon eje omo yoruba ti awon fulani ti pa lo maa da Gani Adams lejo .
Oun gaan alara se baba Fasoranti yen fi omo won ti fulani pa si ore yen fi ra emii won ni ?abi kilo tie de na kilo nse awon baba agba iya wonwonyi na ?se awon ti won ti nwo inuu koto lo bayii niwon tun npariwo restructuring ?bawo ni awon baba wonyii se ya oloriburuku eda bayi ? Lagbara Olodunmare gbogbo yin lo maa seleya gbeyi aye yin lagbara alale Ooodua Amin ase.
Eku eto baba ekiti Mi beyin ema daruko ENI kankan sugban o gbogbo ENI ti o ba ni ki yoruba ma Kuro ni oko eru wan pare tirantiran pelu ogo olorun.ase ti gun yi lati ode orun.
Awan agba yoruba ko mon wipe baby ti seju.iyalenu loro awan baba yi ma unje fun awan ojulowo omo yoruba ,eyin baba yi ki lode ti ikan tiyin ki unte yin lorun
Awon Baba ti won ti de enu bode ti won yi wa owo kinni won fe fi owo na se, iru Baba Fashoranti ti won pa omo e ti o yen ki o ma pariwo Yoruba Nation ti ouna nwa restructuring awon agba oshi awon kidnappers awon Yoruba Gumi. Gbogbo won ni Olorun ma dajo fun.
Absolutely,I love and like this Baba Ekiti. You're fantastic sir .
Baba Ekiti, e ku igbiyanju. e si ku Oro ilu, ole nla ni gbogbo won. Yoruba Nation la fe. No going back.
Ekuse takutaku Oluwa Olodumare aranwalowo Amin o. Yoruba Nation no going back, Yoruba Nation now now now. God bless all Agitators for Yoruba Nation. God bless Prof Akintoye Adebanji, Chief Sunday Adeyemo Igboho Oosa and all people of Yoruba Land. Orilede Yoruba la fe ni kia kia kia. Ase Eledumare. God bless all people in house.
We want genuine country.
YORUBA YORUBA YORUBA NATION IS OUR CHOICE.
Baba Ekiti e ku ise takuntakun, ile Yoruba a gbe yin. Wahala yin koni jasi asan loruko Jesu Amin. Olorun Eledumare a se atilehin fun yin
Yoruba Nation will come to stay "LAGBARA EDUMARE".
Well done baba Ekiti, yoruba nation no going Back.
His purpose of being Are ona kakanfo has been defeated because he's not doing anything for Yoruba race.
Weldon Baba Ekiti.
Cry for restructuring shall never rise again IN JESUS NAME.
Baba Ekiti e ku ise takuntakun ❤❤❤
We have gone so far. Than to go back. Backwards never, forward ever. Yoruba nation is our own mandate.
O maa pa Gani Adams lori adabi to ba ti je pe oun lo da EGBE O P C sile .laipe laijina lagbara Alawura alale Ooodua maa ye Gani Adams lese gbogbo awon eje omo yoruba ti awon fulani ti pa lo maa da Gani Adams lejo .
AMIN AMIN ASE EDUMARE 🙏🏿🙏🏻🙏🏿
Ase wa ni ti ireke. Ase EDUMARE. God bless you sir, correct. Awa o mowon o yce yeye council of elders ni won
E ku ishe o! Up Yoruba Nation! No going back 😮.
Ole ni gbogbo won. (Yoruba nation we want.)
ARIWO restructuring KO NI GBERI MO LAGBARA EDUMARE.
Awon agba were ni won.OLOSA OLOSI OLORIBURUKU NI WON
TINUBU LOMA KO WON JO.
ASIRI WON TI TU.
AWON ONILE AJE WON NIYA.TOMO TOMO WON.
OLE OLORIBURUKU LEADERS
Ase Edumare
Gani ko lagbara ojo ni Gani alaso funfun olopa iyonu😂loogun ojoo
Yce oku ninu alaye ole ole ole Yoruba nation now now now
God bless u sir
Baba Ekiti oluwa ma wa pelu yin ni igbagbogbo masebinu ase yori
Can we please know those people call themselves Yoruba Council of Elders.
Awon Agba Oofo Mad people all over
Oun gaan alara se baba Fasoranti yen fi omo won ti fulani pa si ore yen fi ra emii won ni ?abi kilo tie de na kilo nse awon baba agba iya wonwonyi na ?se awon ti won ti nwo inuu koto lo bayii niwon tun npariwo restructuring ?bawo ni awon baba wonyii se ya oloriburuku eda bayi ? Lagbara Olodunmare gbogbo yin lo maa seleya gbeyi aye yin lagbara alale Ooodua Amin ase.
No going back, Yoruba nation now now now.
E jowo e ma binu sir baba le kiti lo ye ki ng ko ti mo wa lo ko baba lu je sha mo ti se a tun se
After Shetima said restructuring my foot it is then the afenifere wants it? They are hopeless agba iya. Yoruba Nation no going back.
Eku eto baba ekiti
Mi beyin ema daruko ENI kankan sugban o gbogbo ENI ti o ba ni ki yoruba ma Kuro ni oko eru wan pare tirantiran pelu ogo olorun.ase ti gun yi lati ode orun.
E ku ETO BABA EKITI ,YORUBA NATION NO GOING BACK
Agba iya ni won ole ni awon ti won PE ra won ni yce
Y.C.E is full criminality illegality no body send them they can not speak for Yoruba. Great Prof. Banji Akintoye, Great Sunday Igboho
Restructuring is dead,(is kuu)
Awan agba yoruba ko mon wipe baby ti seju.iyalenu loro awan baba yi ma unje fun awan ojulowo omo yoruba ,eyin baba yi ki lode ti ikan tiyin ki unte yin lorun
Good job my sister
Ki lo de ti imo awon Omo Yoruba ko Fi sokan bayi nitori Olorun, e je ki a ronu, se oko eru yi ni a maa ku si ni?
Awon Baba ti won ti de enu bode ti won yi wa owo kinni won fe fi owo na se, iru Baba Fashoranti ti won pa omo e ti o yen ki o ma pariwo Yoruba Nation ti ouna nwa restructuring awon agba oshi awon kidnappers awon Yoruba Gumi. Gbogbo won ni Olorun ma dajo fun.
Eku eto ko ti le yewa mo ni PA awon agba won yi mo
Baba L'Ekiti gbosa yin X 7. YCE ọfọn ni wọn!!! Pls NAME & SHAME THEM NOW!!!
Baba Ayiloge and cohort are confused human being - O L E EEE
YCE Yoruba criminal Elders
Yoruba council of Eedà
🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣
All what tinubu said,has he done any one of it.
Yoruba nation no Going back.