WON FE FI NATIONWIDE PROTEST YI GBA IJOBA LOWO TINUBU

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 6. 09. 2024
  • E WA GBO ALAYE ORO

Komentáře • 57

  • @olusolaayindefakeye4426
    @olusolaayindefakeye4426 Před měsícem +7

    Divide and Rule game can not stop us from protesting

  • @user-jg1fw5xj1i
    @user-jg1fw5xj1i Před měsícem +1

    Well done 👍. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.

  • @PastorRufus01
    @PastorRufus01 Před měsícem +5

    The fact that this man said he is man of God is very annoying.
    He should leave wherever he is and come to Nigeria to experience what we are saying.
    It is so sad those who should know are ignorant.. What benefits are you getting from the current government
    Should we all die before Tinubu does whatever he wants to do?
    Epi npa Ara ilu. Ibiti oti ye ka ba ogbon ago la nba ni be.
    Kini awon baba yi gba lowo Tinubu.?
    These types of baba is why the Youth don't listen to the so called leaders
    Tori ihekuje na ni
    All these tribal bias are useless. Yorubas will come out enmass. The Yorubas will be in majority. It is in our culture to throw off oppressive government.
    Tinubu cannot make us to suffer and tell
    us we cannot cry alout.

  • @user-xb5qj5ny2w
    @user-xb5qj5ny2w Před měsícem +2

    Aile soro ibere oriburuku peaceful Protest is a right and a way to correct wrong doings of bad government.

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 Před měsícem +1

    Arakunrin baba onifila eleti aja yi ko gbadun rara. Arakunrin na ti fi ori gbale pelu isokuso ton so. Baba yi ko pe oluorogbo, ko pe atewonran, ko pe obaluaye ati ogun or shanponna nigbati tin won ti npa omo Yoruba. Awon ole alatenuje ni awon baba adanun wonyi.

  • @debbydare9720
    @debbydare9720 Před měsícem

    Well done Arole Baba 10 10. Whatever that would make Yoruba Nation to become a reality should happen sharp sharp. In a situation like this, it's easy to identify the wise ones. The two people that were brought to your show did not Speak wisely. There's no truth in what they have said. What do we expect from an elderly man who put on head gear instead of a cap? Yoruba Nation no going back.

  • @user-xb5qj5ny2w
    @user-xb5qj5ny2w Před měsícem +1

    Taking or sending Tunubu's government out of power is not the issue but to advise him and his cohorts in power to have a rethink, do the needful as per his promises. God help us all.

  • @bamideleigbamole8844
    @bamideleigbamole8844 Před měsícem +1

    If Yoruba indigenous peoples did not come out for protests other regions would see Yoruba as a betrayal this is nation wide issue of bad governance, but they will harm or hurt Yoruba land for not joining them.

  • @olatoyeakerele183
    @olatoyeakerele183 Před měsícem

    E ku ise o. Oodua a gbe yin o❤❤❤

  • @michaeloyinlola120
    @michaeloyinlola120 Před měsícem

    Baba igbomina, koni daa fun yin, tomotomo lagbara Olorun Oba Onimajemu. Adabi ti awon omo yin ba pelu awon ti awon fulani ti padanu. Oloriburuku baba ofo baba adanu...ile igbomina maa bi yin, ayafi ti e ba se daradara.

  • @hayjayprint1275
    @hayjayprint1275 Před měsícem +1

    💯✅

  • @olusolaayindefakeye4426
    @olusolaayindefakeye4426 Před měsícem +1

    The protest must come up

  • @VictoriaOjo-nq8hd
    @VictoriaOjo-nq8hd Před měsícem

    E jowo e ba wa kede ki won ma ba nkan je nile Yoruba, Olorun ma gba gbogbo ogo ninu protest na , a ni ri ogun itajesile o , abo Olorun ma daju , e ku eto Olorun a ma fun yin se , iru baba yi ko se ba Tinubu soro ķo fi asiko yi pin Nigeria , ti won fi npitan

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 Před měsícem

    God bless you richly Arole, may Olodumare continue to protect and guide you and your families

  • @user-xb5qj5ny2w
    @user-xb5qj5ny2w Před měsícem +2

    This man with abeti aja cap is one of those who are working against the return of Sunday Igboho to Yoruba land. Nonsense.

  • @adeloyesunday8853
    @adeloyesunday8853 Před měsícem +1

    Baba ku tv

  • @adebimpeadebayo1184
    @adebimpeadebayo1184 Před měsícem

    Arole baba 10-10 why this baba did not made mentioned Fulani that did not allow farmers to go to there farm

  • @maryogunkuade2560
    @maryogunkuade2560 Před měsícem

    Àwọn ebí restructuring ati regional government lo njade sọrọ yi o. Gbogbo owo ti e gbà ni e máa ná tán. E ye hale mọ wa. Oju ti ti gbogbo yín bayi o.

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 Před měsícem +1

    The protest must be done

  • @olusolaayindefakeye4426
    @olusolaayindefakeye4426 Před měsícem +1

    A ma protest b'e fe b'e ko

  • @maryogunkuade2560
    @maryogunkuade2560 Před měsícem

    Se wọn nsa sí wọn ni? Wọn nsa sí ìwo àti ebí e. Àwọn alabosi. O o ni mọ pe ebi npa wọn nígbàtí o o si nile. Sebi ẹyin náà ni e mba wọn launder owó. Iba dára ki o ma tie sòrò rárá. Depo ti o máa fi ori gba èpè alajobi.

  • @maryogunkuade2560
    @maryogunkuade2560 Před měsícem +1

    Awon alajebanu àgbà ìyà. Yorùbá wo lo wà in charge?

  • @josephsamsonolugboyega5061
    @josephsamsonolugboyega5061 Před měsícem +1

    Babà arole EKaro ooo,,,🤍🤍🤍🤍🙏👍,,,,, EKU Eto ooo

  • @adebiyioluwaseyi50
    @adebiyioluwaseyi50 Před měsícem

    Abanilojuje ni awon baba oloriburuku yi

  • @OlukokunEmmanuel
    @OlukokunEmmanuel Před měsícem

    Ẹku eto Sir

  • @Rasheedismail624
    @Rasheedismail624 Před měsícem

    ❤🎉❤🎉🎉

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 Před měsícem

    Se baba yi tie ri owo ran omo ni school gann. Awon baba elemu😮

  • @AbimbolaOdetoyinbo-vx4xx
    @AbimbolaOdetoyinbo-vx4xx Před měsícem

    Baba arole eku ise , eyi te play oro baba radarada yi to jare ika agba rendered jatijati ni

  • @estherfawibe1280
    @estherfawibe1280 Před měsícem

    Arole eyi tun ya to laro yioooo

  • @michaeladewole5781
    @michaeladewole5781 Před měsícem

    Thank you, Baba Arole. 👍👏👏👏

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 Před měsícem

    Gbogbo awon baba ofo yi, se Tinubu mo iyalaya ati babanlaku won ri ni. Awon baba iranun, baba adugbo. Iru awon baba yi o mo ju pe kan won play ayo olopon ati dat ni adugbo.

  • @Rasheedismail624
    @Rasheedismail624 Před měsícem

    God bless you so much 🎉🎉

  • @user-qi8ex5xu1i
    @user-qi8ex5xu1i Před měsícem

    Se won ki nku si Jerusalem? Let's go to the right place don't discrimellate let's go to where shoe is horting our leg

  • @oluwolepalmer1970
    @oluwolepalmer1970 Před měsícem

    Ase o

  • @atunwaabiodun3988
    @atunwaabiodun3988 Před měsícem

    Tinubu lo mu Buhary wa se president Nigeria

  • @DayoAdewale-os3jz
    @DayoAdewale-os3jz Před měsícem

    Baba tounsoro sekori bi nijeria seri no eunbija tiniubu eobija mekun niun

  • @user-qi8ex5xu1i
    @user-qi8ex5xu1i Před měsícem

    We need our nation we we are beside true Yoruba nation this baba seek upstairs nah oooole they don collet money from gomina

  • @BidemiOlugbade
    @BidemiOlugbade Před měsícem

    Yoruba nason lafe

  • @EdeniyiRamanoubabalola
    @EdeniyiRamanoubabalola Před měsícem

    Ekou. Eto

  • @TundeOyenekan
    @TundeOyenekan Před měsícem

    Arole e jowo e gbe number yin oju screen

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 Před měsícem

    Arole wo sere fun aworan ti o gbe jade yi aiye e a dara , tomo taya ati awon ebi re lase Edumare

  • @mohamedbombata739
    @mohamedbombata739 Před měsícem

    Baba Arole this man does not know what he is taking about. Tinubu is killing Yoruba people. I said it again this man doesn't know what he is talking about. Tinubu has destroyed Yoruba land. Let him his mouth shut.
    This man is telling the truth on like the other guy who call himself pastor. I hope the youth hear you.

  • @user-ck1lr5sq6z
    @user-ck1lr5sq6z Před měsícem

    Dindinrin ni ogbeni yi, Tinubu lo sise fun. Se bi diasperal to wa se ri re. Ode to nsoro yi ti nwon ba fe gbe nisinyin o ma pariwo pe American citizen ni ohun. He has already failed.

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 Před měsícem

    Awon baba ofo ati adanu

  • @ijayaijaya6577
    @ijayaijaya6577 Před měsícem

    Nobody can stop protest in lagos and stop promoting propaganda of fools

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 Před měsícem +1

    Tinubu is a wicked and wickedness government

  • @ijayaijaya6577
    @ijayaijaya6577 Před měsícem

    This baba is talking rubish and blind folded agbalagba

  • @tolulopeajayi8852
    @tolulopeajayi8852 Před měsícem

    Arole good morning, why do you do your hair like this?, you look good before than this, please don't do your like woman again

  • @user-xf1df6gl3l
    @user-xf1df6gl3l Před měsícem

    Baba Arole i disagree with you in regarding Eko, because the destruction made during endsars
    They intentionally destroy Yorubaland , which no one can do in igbo lands
    Its better you speak with them because you said they are your friends not to destroy anything in Yorubaland
    Baba mi