Ogboju Ode|Mopa Alujannu Igala toni Ota ninu|Awon omo ijimere fe pami, opelope afeeri ti molo

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 21. 09. 2023
  • Alujaanu Olofin laaja ma nfu wa ni eran ti aba fun ni Ekuru ati Esuru|Eledua lo yomi lojo ti mo wo inu iho ti konipekun
  • Zábava

Komentáře • 43

  • @madjidakandeoba
    @madjidakandeoba Před 9 měsíci +1

    Èku isè oooooo, èmì yìn o gùn ooooo

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před 9 měsíci

      Àdúrà yin yo gba lagbara Eledua

  • @moseslapade3733
    @moseslapade3733 Před 4 měsíci

    Layolayo.....eba wa gbe awon.ogboju agbegilodo wa sori eto ooo ogun ayena.😅

  • @SupremeAfricaKing
    @SupremeAfricaKing Před 9 měsíci +2

    Ese you bringing us things that we need . Our cultural heritage will continue forever. Thanks

  • @oludjobimuhammad1654
    @oludjobimuhammad1654 Před 9 měsíci +2

    Eseun olotu olorun yoso agbara di otun

  • @olalekanrabiu6240
    @olalekanrabiu6240 Před 9 měsíci +2

    Edakun emi fe eyonu to gbona gan ooo 👏👏

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před 9 měsíci +2

      Lol.. Eledua àti àwọn to gbé Ile aye lowo yọ yọnu siyin

  • @Emperor9443
    @Emperor9443 Před 9 měsíci +3

    Ẹ kú iṣẹ́ takuntakun bekear television. Ẹ jọ̀wọ́, ẹ bá wa béèrè l'ọ́wọ́ olúọ́dẹ Alékúwodò pé kíni ìyàtọ̀ láàrin "Ìjálá" àti "Ìrèmòjé"?

  • @olawaleakanbi3099
    @olawaleakanbi3099 Před 9 měsíci +2

    ❤❤❤

  • @AbionaKabir-wo2xl
    @AbionaKabir-wo2xl Před 9 měsíci +2

    Bikear tv e se o, e fun wa lasiri loni leyin bi osu meta ti e ko ti fun wa lasiri mo , Ogun o ma basiri yin o .

  • @Sterling98
    @Sterling98 Před 9 měsíci +3

    Thumb up BIKEAR 👍 TV.

  • @deep.679
    @deep.679 Před 9 měsíci +2

    Bikear! E ṣeun wa o. A dúpẹ́ lọpọlọpọ.

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před 9 měsíci

      Ibà yín Baba! Eledua kọ́ni fiyin sile sir

  • @olawaleakanbi3099
    @olawaleakanbi3099 Před 9 měsíci +3

    Ekuse takun takun oo opolo yín oni doba ooo

  • @emmanuelwakanda8360
    @emmanuelwakanda8360 Před 9 měsíci +1

    Always on point

  • @iluminar_official
    @iluminar_official Před 5 měsíci +1

    Great job @Bikear TV. My only question which has always baffled me is this: With all our spirituality, power and knowledge of metaphysical, how were the white folks able to conquer us and take our people as slaves??? I mean come to think of it, how many of those white folks came to Africa, and they succeeded in conquering and taking our people as slaves. Please I need answers to this questions and if you will be an objective investigative journalist and a promoter of Isese, you will throw these questions open to our brave and powerful hunters and Isese custodians. Thank you.

  • @samuelotunba9984
    @samuelotunba9984 Před 9 měsíci +1

    Good job

  • @annamendy1333
    @annamendy1333 Před 9 měsíci +2

    Ekueto sir setiriwipe ojurawonlo awon baba wa Lati Ilesha lo si ekiti won ju ti awon ilu Toku lo.

  • @samuelotunba9984
    @samuelotunba9984 Před 9 měsíci +1

    Great one

  • @samuelotunba9984
    @samuelotunba9984 Před 9 měsíci +1

    Good luck

  • @user-dm8tg1oz7b
    @user-dm8tg1oz7b Před 9 měsíci +2

    Thanks bikeatv

  • @samuelotunba9984
    @samuelotunba9984 Před 9 měsíci +1

    Good

  • @TimileyinJohnjimoh-fm8lt
    @TimileyinJohnjimoh-fm8lt Před 9 měsíci +1

    Looto iwin ni ijimere

  • @user-bq9dr4fw6e
    @user-bq9dr4fw6e Před 3 měsíci

    Edakun èso fun awon Baba ti è ba sé éto wipé kiwon maso édé Yoruba titi gbogbo wa gbo

  • @annamendy1333
    @annamendy1333 Před 9 měsíci +2

    Hello sir ejowo ebawaya ni Erinmo ki e bawa interview Baba ode bii Meiji sir

  • @omodupe7412
    @omodupe7412 Před 9 měsíci +1

    Bikear TV Plsssss can you subtitle the animal names. Pls

  • @taiwoakinlolu4722
    @taiwoakinlolu4722 Před 9 měsíci +1

    Well done sir for the great job you are doing all the time for the benefit of humanity. However, getting in touch with you is almost impossible as another person would pick the call sir. Is there anyway in which I can get in touch with you on phone directly. I am a Biker fan club.

    • @BikearTv
      @BikearTv  Před 9 měsíci +2

      It is against the ethics of this profession and company's regulation to do so sir. Those incharge of Admin. Will pick up WhatsApp calls and attend to your needs accordingly. But patience is needed because it's on first come first serve basis sir.thanks

  • @olawaleakanbi3099
    @olawaleakanbi3099 Před 9 měsíci +1

    ❤❤❤