NITORI TINUBU: AWỌN OLOṢELU FẸẸ DA WAHALA NLA SILẸ NILẸ HAUSA

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 8. 07. 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
  • Zábava

Komentáře • 28

  • @RazeedAyinki
    @RazeedAyinki Před 13 dny +3

    Olorun osaun wa Amin

  • @LukmanAgbaje
    @LukmanAgbaje Před 12 dny +2

    Hmmmmm Nigeria

  • @adebayoolayemi4865
    @adebayoolayemi4865 Před 12 dny +3

    Asa buruku ni l'ooto, sugbon t'o ba je wipe ohun ti o le mu nigeria pin niyen, ki tinubu tete f'owo si.Ti a ba pin tan Olorun a fi ona abayo koro n'ibe han wa.

  • @timothywale8055
    @timothywale8055 Před 13 dny +3

    Hmmm, kangun, kangun, kangun, oma kangun sibikan saa ni, Yoruba Nation ni ona abayo si gbogbo rogbodiyan yii , ki wahala le dopin

  • @user-vg8nm3wt9d
    @user-vg8nm3wt9d Před 13 dny +1

    Walahi oloselu nigeria yoo pa nigeria run

  • @biochar.
    @biochar. Před 12 dny +1

    Na Bobrisky cause am sir

  • @alababalogun3362
    @alababalogun3362 Před 8 dny

    YORUBA NATION 1

  • @bigbirdrewire
    @bigbirdrewire Před 13 dny +5

    Koni dafun gbogbo won Nile ahusa

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm Před 12 dny

    Igbawo ni rogbodiyan oni sele won kan nfi pamo ni ki kaluku mura sile

  • @giveway...6838
    @giveway...6838 Před 13 dny +3

    Were ni okunrin yii jare!
    Awon Oloselu yii sha....

  • @AyotundeOjuade
    @AyotundeOjuade Před 12 dny

    Idagbasoke ni Nigeria abi kileunwi, nobody thinks of stable electricity, no electricity no development, no electricity no security, no electricity no job advantages, refinery is there without renovation, just dey play, awon ika eda gbogbo.😢😢😢😢😢

  • @odunolaalli6773
    @odunolaalli6773 Před 13 dny +1

    Ki ijoba ya gbe okunrin Yi lati wa so tenu re.

  • @MrTjogunsola
    @MrTjogunsola Před 13 dny

    Awon ika eniyan eje kiwon danwo Naija tan niyen.

  • @SoulyaAtanda
    @SoulyaAtanda Před 13 dny

    Iru radarada wo ni eleyi tan so

  • @Omowunmi0412
    @Omowunmi0412 Před 13 dny +1

    Ki I se Awon Hausa awon Fulani ni won nse gbogbo nkzn yi ..Sugbon SAMOA yen ko to si Nigeria rara .Asise nla ni eleyi ma je ti Tinubu ba fowo si .Awon ile Hausa o ni gba eleyi o .A tete ya kiakia lati pin Nigeria is were ni

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 Před 12 dny

    Ohun ti oju won wa ni oju won ri ni Nigeria, ki Olorun wa pelu Omoyele Sowore to fi ojojumo wa leyin Mekunnu.

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp

    OMG OOO

  • @AzeezJeleelOlanrewaju

    Igbos and lie are and one and two

  • @imoleadini
    @imoleadini Před 12 dny

    Edakun.sewonfi kan.baba wereyi.wipe komo.yawoka kilonfowo nase eyin.baba oloribu.akosi.bero baba.onigbese onigbese.gbogbo gbani.wonwa owoyiya.ka.awon.onise.minju owoyiyalo baba Tinubu.eyeyawokamo wonfowo yiya.seyinni eyin.jereni afowo yiyasa.ojigan niyin.ninu owo.yiya.sele san gbese tejeyi.keto kuro.nipo.eyin babaosi.akotiletayi.efakun.ewabi.bosilo.ojare owoyiya.sasani.enigbo.royinpe wonkowo.wole afikemo.yawo nigbogbogba.bopolo yin
    Obamo ntiose mo baba.ewabi gbalo.ojare baba.onigbese.niyin

  • @BossaFola
    @BossaFola Před 9 dny

    Ejo ki la tan ra fun? Ai mon oye omo Igbo in diaspora same gender fe ara won

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff6458 Před 13 dny +1

    Ki ALLAH ma sowa

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm Před 12 dny

    Tinubu kounse Muslim gidi koun kirun tele igba to fi agidi je aare loso arae di Muslim oju aye

  • @Jimoh.Gaskia
    @Jimoh.Gaskia Před 13 dny

    Kiwon.odale.oro.tiowanileyi.enihawifun.oba.Olorun..jekiogbo.tiebagbagbe.Baba.Akintoye.wiwipe.kapin.awon.ojelu.yi.nitori.imotiarawon.nikan.awon.gomina.ile.yoruba.yi.tigbagbepe.oro.masunkikiku.ita.yiose.nipa.onikaluku.ounti.onikalukubase.oro.itani.leyin.waola