NIGHT OF DELIVERANCE - ORU ITUSILE // 25-JULY-2024

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 6. 09. 2024
  • @CAC COVENANT OF MERCY
    DISCLAIMER!!!!
    We own no copyright license for all Music used on this program. We give credit to the music owner, producer, and record label.

Komentáře • 42

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Ogun to foru wonu aye mi, to foru wonu aye awon omo, ki ile oni to su, jade ki o wole lo loruko Jesu, gbogbo owo ija ogun ninu aye emi ati awon omo mi loruko jade ki o wole loruko Jesu, gbogbo ogun maa jade pelu owo ina ki o wole lo loruko Jesu

  • @AbeOmobolanle
    @AbeOmobolanle Před měsícem

    God of Taiwo Ojo thank you!! 💃💃💃💃💃💃💃💃💃 God has done it 👏👏👏👏

  • @user-rb6xh9pv4s
    @user-rb6xh9pv4s Před měsícem

    God please have mercy upon my life 🙏

  • @ChildofGod98765
    @ChildofGod98765 Před měsícem +2

    There are so many different obstacles that I face as a single mom. Some days I want to give up. God give me strength. I’m struggling to make ends meet. Both of my sons are special needs and require much from me. I keep faith because I know that God will provide. So as I struggle to buy groceries for my children, and as I struggle to pay rent every month. I turn to you Lord Jesus for help.❤️

    • @israelaustinleke6431
      @israelaustinleke6431 Před měsícem

      God will come through for you. Please dont give up. Keep hope alive. God has a greater plan for you.

  • @christiana1037
    @christiana1037 Před měsícem

    Amen in Jesus name

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Ni oruko Jeeesu, gbogbo eniyan buburu to yi mi ka, Oluwa fi iku fa won tu, gbogbo ika eniyan gbogbo to yi aye awon omo mi ka, Oluwa ba mi fi iku fa won tu, gbogbo emi okunkun gbogbo oso ati aje to yi aye emi ati awon omo mi ka, Oluwa fi iku fa won tu kiakia, Oluwa fi iku le won laye loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Ohun ti aye gba lo to wa aye mi duro, to da aye awon omo duro, Oluwa fi aanu da won pada, Oluwa da won pada fun wa loni, ohunrere gbogbo ti ota ti gba lo lowo wa, aanu da won pada loni loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Ohun ti aye gba lowo mi, ti won gba lowo awon omo mi, ti aye wa fi wa lojukan, Oluwa ba fi aanu da pada loni, Oluwa da won pada, ire, aanu iserere, oore-ofe gbogbo ti ota ti gba lo, Oluwa fi aanu da won pada loni loruko Jesu

  • @samuelomoboriowo2485
    @samuelomoboriowo2485 Před měsícem

    Hallelujah hallelujah hallelujah

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    I connect my children and my family into this prayer ijn

  • @TaiwoBolanleBolarinwa-et8ng

    I connect my siblings and I to this altar of fire and prayers for divine deliverance victory and restoration of glory in Jesus mighty name

    • @raphaelomozokpia4029
      @raphaelomozokpia4029 Před měsícem

      Thank YOU LORD JESUS Christ of Nazareth for another privilege to Worship and Praise at Your Loving Feet, I am deeply Grateful....

  • @fatimalassissi6415
    @fatimalassissi6415 Před měsícem

    Thank you jesu ogoôoooooooôogoooôgoôoo

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    God bless me

  • @kemiojomartin6272
    @kemiojomartin6272 Před měsícem

    Amen Amen Amen ni oruko Jesus

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Oluwa mo fe soro, fun mi ni ohun ti enu mi maa fi toro, awon omo mi fe fohun nibi giga, Oluwa fun won ni ohun ti enu won maa fi gboro, agbara ati ase ti enu wa maa fi toro ninu ile baba ati iya nibi ti a n gbe laarin ebi gbogbo Oluwa yonda re fun mi ati awon omo mi loni loruko Jesu

  • @christiana1037
    @christiana1037 Před měsícem

    Thank you Lord in the name of Jesus Christ

  • @christiana1037
    @christiana1037 Před měsícem

    Amin

  • @TaiwoBolanleBolarinwa-et8ng

    I connect David Amromaghwo to this altar of fire and prayers for divine deliverance intervention victory protection and direction in Jesus mighty name

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Oluwa ki ile osu yi to su, iranlowo ti aye mi ati awon omo mi nilo lati san gbese to n dawa duro, fi aanu pese re fun wa, je ki oore-ofe yonda re fun wa ni ona ki a ko lero, je ki aanu fohun fun wa, fi aanu yi wa ka loruko Jesu

  • @ibrahimowolabi-il2mc
    @ibrahimowolabi-il2mc Před měsícem

    Hallelujah

  • @biolasaka9183
    @biolasaka9183 Před měsícem

    Amin loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Amin Jeesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    Aamin loruko jesu

  • @christiana1037
    @christiana1037 Před měsícem

    Aminoooooooooooo Jeeeeeeesu

  • @matensunruth9523
    @matensunruth9523 Před 14 dny

    Aaaaaaaaaamin loruko Jesu

  • @christiana1037
    @christiana1037 Před měsícem

    Amin Jesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    dapada

  • @christiana1037
    @christiana1037 Před měsícem

    Baba mo fę soró fun mi nkan ti ma fi soró

  • @josephinefolasadetiamiyu3164

    OLUWA MO FE SORO FUNMI NII NTI ENU MII O FII TORO

  • @christiana1037
    @christiana1037 Před měsícem

    Amen in Jesus name

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Amin Jeesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    Aamin loruko jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje4238 Před měsícem

    Amin Jeesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    Aamin loruko jesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    Aamin loruko jesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    Aamin loruko jesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    Aamin loruko jesu

  • @AmudatFunmilayo
    @AmudatFunmilayo Před měsícem

    Aamin loruko jesu