Olorun Odekunle Epaphras, ki odun yi to pari, maa fi nkan rere lole, awon omo mi maa se ifilole ohun pataki kan, Olorun maa mu mi de ile to teju tomotomo loruko Jesu
Olorun Odekun Epaphras, saanu mi ki n ri oloore to maa fa awon omo mi lowo soke, to maa mu won de ilu oyinbo, aanu to maa bi owo nla fun mi, to maa mu mi de ile ileri mi, aanu to maa so awon omo di nla loruko Jesu
Ni oruko Jesu, gbogbo awon omo mi ko ni di ero eyin, Raphael, o ko ni di ero eyin, Emmanuel, o ko ni di ero eyin Adeyemi gbo oro Oluwa o ko ni di ero eyin, emi ati awon omo mi ni oruko Jesu a ko ni di ero eyin, a ko ni lo seyin mo loruko Jesu
Olorun Ojiji ta emi naa lore ohun rere kan pataki lose yi, ta awon omo mi, Sunday, Emmanuel lore ohun pataki kan lose yi Oluwa, mu inu mi dun lori won de le loruko Jesu
Ni oruko Jesu, Emi Mimo ooo, saanu mi ki oloore ati alaanu wa mi ri ki won fi owo nla saanu mi, ki won fi aanu fa awon omo soke, ki won fi aanu ran mi lowo lori project ati kole mi, Oluwa je ki n ri aanu to tobi gba lori awon omo mi, je ki Raphael ri aanu to tobi gba lowo oga ise re, je ki aanu to tobi ya lu Emmanuel lowo oga ati awon ore re loruko Jesu
Maa lo siwaju, awon omo mi maa siwaju, awon omo mi maa ni progress, aye mi maa ni progress, emi ati awon omo mi maa progress loruko Jesu
Amin amin Amin amin Amin amin
Amin Jeeesu
Amin loruko Jesu
Angel Odekunle epaphras jeki ri Anu gba ninu ose Yi osu Yi odun Yi ni oruko Jesus Amen 🙏
Thank you Jesus
Olorun Odekunle Epaphras, ki odun yi to pari, maa fi nkan rere lole, awon omo mi maa se ifilole ohun pataki kan, Olorun maa mu mi de ile to teju tomotomo loruko Jesu
God by your mighty hand, restore the glory of God's Heritage business for me and family as we enter the month of July in Jesus name.
Olorun Odekun Epaphras, saanu mi ki n ri oloore to maa fa awon omo mi lowo soke, to maa mu won de ilu oyinbo, aanu to maa bi owo nla fun mi, to maa mu mi de ile ileri mi, aanu to maa so awon omo di nla loruko Jesu
Olorun Odekunle Epaphras, je ki n ri aanu gba jale ose yi, je ki awon omo mi ri oju rere oga ise ati alabasisepo won lose yi loruko Jesu
Mo tin tele woli mi Odekunle Epaphras ma jere ni Oruko Jesu
More anounnting sir
I receive my baby and my shop in Jesus name
Iroyin ayo temi naa fere de, iroyin iyanu temi ati awon omo mi naa ti de tan loruko Jesu
This year me and my son will progress in Jesus mighty name
Dad i ear you every morning more Anoiting sir
Malo siwaju awon Omo mi alo siwaju loruko jesu
Thank you Lord 🙏my prayers are answered
Ni oruko Jesu, gbogbo awon omo mi ko ni di ero eyin, Raphael, o ko ni di ero eyin, Emmanuel, o ko ni di ero eyin Adeyemi gbo oro Oluwa o ko ni di ero eyin, emi ati awon omo mi ni oruko Jesu a ko ni di ero eyin, a ko ni lo seyin mo loruko Jesu
Thank you lord jesus hallelujah 🙌
Amin loruko jesu Emi ni irohin Ayo kan Amin
God bless you sir, more anointing sir
Olorun Ojiji ta emi naa lore ohun rere kan pataki lose yi, ta awon omo mi, Sunday, Emmanuel lore ohun pataki kan lose yi Oluwa, mu inu mi dun lori won de le loruko Jesu
I received my shop in Jesus name
Thank you Jesus Christ
Thank you Lord
In the month of July I want the grace to excel in all areas
Ninu odun yi wether the devil like it or not, emi ati awon omo maa progress, we are moving to the next level in Jesus name
Amin Amin Jesu
Ni oruko Jesu, Emi Mimo ooo, saanu mi ki oloore ati alaanu wa mi ri ki won fi owo nla saanu mi, ki won fi aanu fa awon omo soke, ki won fi aanu ran mi lowo lori project ati kole mi, Oluwa je ki n ri aanu to tobi gba lori awon omo mi, je ki Raphael ri aanu to tobi gba lowo oga ise re, je ki aanu to tobi ya lu Emmanuel lowo oga ati awon ore re loruko Jesu
Thank you God
Paid thank you Jesus
Thank you for all of you that bless woli me
May Almighty bless you all more in Jesus name 🙏
Thank you Jesus 🙏
Honestly, the truth always come out from Man of God, Odekunle Epaphras.
Amen in Jesus name ❤
Woli odekunle epaphras is my prophet ooo
I will do my own sir just help me manage it sir
I heard the testimony on 7/6 2024
Loruko Jesu majere lose yi
Ma jere lo se eee
Labe Woli Odekunle Epaphras aye mi ati awon aye awon omo mi maa lo siwaju, aye mi maa lo siwaju, aye awon omo mi maa siwaju loruko Jesu
Ma jere lose yi
Amin Jeeesu