O ma se o! Watch the last journey of Prophet Oshoffa and how he had a fatal accident with his aides

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 25. 11. 2022
  • #celestialchurchofchrist #osofa #churchgist

Komentáře • 34

  • @issajimoh2701
    @issajimoh2701 Před 3 dny

    Am a Muslim, this story is saddened but we have to accept it has will of God Almighty ..... From Almighty we come and we must go back to him.

  • @thompsonaminu6721
    @thompsonaminu6721 Před 3 měsíci +1

    Papa o sokun, rara mo wa nibe lojo na. Emi ni mo ka eko kika ikini. ( First Lesson) Baba Bada ti bere iwasu ki Papa to de. Bi ati gbo wipe Papa ti de lesekan na ni Baba Bada sokale lori aga iwasu lati pade Papa ati lati gbe won wole. Lehin ti ati ki won wipe "EKA BO SIR, EKU ISE OLUWA, OLUWA ASO AGBARA DOTUN , E O SASEYE, E O SASEYEGE " Papa bere nibo ni aba esin de? Baba Bada lori ikunle so wipe iwasu ni a nse lowo. Papa so wipe ki Baba Bada tesiwaju lati ma wasu. Lehin iwasu Papa gba microphone 🎤 won gbadura fun gbogbo Celestial, orilede Nigeria, ati gbogbo agbaye. Lehin eyi ni won sokale lati ma lo si Ibadan. Mo wa pelu awon to sin Papa de isale nibi ti motor won nduro de won. Papa so fun Baba Bada wipe ki awon duro ti ijo. Sugbon Baba Ajanlekoko ni won siwaju ti awako Papa tele ti Baba Ajanlekoko. Baba Abiassi pelu awon osise Papa, inu oko Papa ni won ma nwa. Bi oro se ri niyen. Ki Oluwa Olorun awon BABA wa ki o fun PAPA S.B.J. OSHOFFA ni isinmi ayeraye. Ki ijo mimo ma gberu siwaju ati siwaju loruko JESU KRISTI Aminu.

  • @adelekesholly9811
    @adelekesholly9811 Před rokem +2

    Am not a cele but this story touch my heart want make me cry

  • @hy-profarmsagroalliednig9610

    The hospital Papa was taken to was First Shedrack Hospital, Association Avenue and not Labi Hospital. Both were in Ilupeju.

  • @GroovyEze
    @GroovyEze Před 10 měsíci +1

    Papa!😭😭😭💔💔💔🤦🏻

  • @keloabecoegaleboe7845
    @keloabecoegaleboe7845 Před rokem +3

    We really want to know what's being said. Kindly translate🙏

  • @ayeshabobray8195
    @ayeshabobray8195 Před rokem +6

    When are you all going to add a translate button for those of us that don’t understand Yoruba?😊

  • @Tktawakalitu-lc5qt
    @Tktawakalitu-lc5qt Před 10 měsíci

    Papa rip

  • @joshuapeter2072
    @joshuapeter2072 Před 7 měsíci

    Rip papa

  • @yemijola4884
    @yemijola4884 Před rokem

    O di dandan ki awon losi ibadan lati lo se ise oluwa . Papa mo wipe acident ni iku wom wa sugbon won fe awon family ri oku won

  • @yemijola4884
    @yemijola4884 Před rokem +1

    Iro patapata ni itan yi. Papa ko fi ese to ile re tio fi pa ipoda. Lati ibere do opin iro ni ,

  • @dorgumercy5780
    @dorgumercy5780 Před rokem +1

    Papa🌈☂️❤️🥺

  • @akannitobi8495
    @akannitobi8495 Před rokem

    Awon akoni sun

  • @oluwatoyinamokeodo4162
    @oluwatoyinamokeodo4162 Před rokem +1

    Papa died in first Shadrach hospital ilupeju,He didn't reach home at all

    • @yemmietitilola2791
      @yemmietitilola2791 Před rokem

      He got home, them was transferred to shadrach hospital at ilupeju

  • @yemijola4884
    @yemijola4884 Před rokem +1

    Papa mo wipe omo ti jese fun won ko paro Sugbon papa ni ise oluwa kose da duro.

    • @limatglobaltemp7181
      @limatglobaltemp7181 Před 8 dny

      Ise Oluwa wo ni ko SE da duro? Se dandan ni ko wa nibi ajodun to Ibadan ni? Abi ijo yen ko ni se ajodun miran mo ni?

  • @yemijola4884
    @yemijola4884 Před rokem +1

    Yoruba otito, pls go to oshoffa's family and ask about the real history, pls i enjoying you but not real at all who ever told you all is not real . Thank s I love you sir. Good job

    • @aniyikaye31
      @aniyikaye31 Před rokem

      The story has been doctored, is different from what I head from oshofa's family

    • @annatitilope3099
      @annatitilope3099 Před 5 měsíci

      Thanks so much the story is wrong ask for real story

  • @michaelking7517
    @michaelking7517 Před 2 měsíci

    What a pity, they should have gone to UCH IBADAN...

    • @limatglobaltemp7181
      @limatglobaltemp7181 Před 8 dny

      It was a very unreasonable decision. Imagine the loss of blood from the accident sport to Ibadan, then to Lagos.

  • @hapexconsulting3789
    @hapexconsulting3789 Před 9 měsíci

    Not Papa (mi-do) but Papa (Re-mi).

  • @yemijola4884
    @yemijola4884 Před rokem

    Papa mo wipe ojo ti mpe sugbon komo ojo. Nitori naa ni papa kose losi ilu oyinbo rara.

  • @yemijola4884
    @yemijola4884 Před rokem

    Ni tori naa ni won se lo di ilu oyinbo rara. Papa mo gbogbo re

  • @OladipupoMoses-wu6qg
    @OladipupoMoses-wu6qg Před 2 měsíci

    R.i.p papa

  • @annatitilope3099
    @annatitilope3099 Před 5 měsíci

    Thanks for wasting my data sir because this story is not real