Baba ogundokun,may you live long sir. Iwo people should have elect you as king, these man call oluwo, Iwo will never mistake again to elect such a man.
May you live long baba Ogundokun ame. Sokoti that's an excellent job, God bless Sir. You know anytime a dog want to go astray such dog will not listen to the owner. We should leave him alone God will take care of that. Baba emape fun wao agba yin yoo dale o amin.
Please Sir, Baba Sokoti stop calling Tahun leader Mufti!!! He lost the Muftihood oif yoruba. Iwo need to take back the Ogun god to its rightful place in the historic palace.
If you like call giveenor Adeleke from now till tomorrow he will pay dead ear to the issues in Iwo, because if he does ut may affect his election for second tenure.. but i can tell you boldly if he is elected for second term,he wilk aurely address these issues ..
Kí àwọn ọmọ ìwo, àwọn ọmọ Ọsun State, Ọsun state Government, gbogbo ọmọ Yorùbá àti ìjọba Nigeria dìde sí ọrọ Mufti Taun Ìwo àti Oluwo kí ó tó di Boko Haram mi o, bí Boko Haram na ṣe bẹ̀rẹ̀ re o
Oloun lo mu gbogbo yin. Eyin le fi amugbo j'oba apapandodo te yan Eni toba to si je. Oju yin ti ja bayi. Aregbesola na ti gba tie. That is the law of karma.
Baba.Ajala tan naa. Eyin na ni e yan oluwo kale . Oro buruku lenu eiye. Bawo ni oba iwo se n'nwe lawani ni ile yoruba. Se larubawa ni o te iwo do ni ? Iwo baba yii naa ni ipinlese rogbodiyan tinbe nile naa .Ti e ko ba fi oselu yan omo ale yii(Rasidi Amugbo) Idamu ati iberu ki o ba ti sele.
Baba Ogundokun,e pe gbogbo awon to ba ye ke pe mora lori oro you.Ke mo be se mayo Oluwo ko to peju,ile iwo ile Yoruba Nation ni o. Baba Ogundokun e pe Are BHT,Gomina Adeleke ati Ooni of Ife pelu awon Oba ile Yoruba to ku.
Oda ran ni omo okunrin to pe ara re ni oba yi won hun fi esin Bo ju ni hooo, aje ni gbe gba emi ele mi ni omo kurin yi ati awon we re ele sin ja gi di ja gan.
Baba Sokoti ekise omobibi ilu Iwo awatiaje omo ilu Iwo ni amo oun ti sele ni igba ti awon baba Ogundokun wani ipo pataki ninu ijoba Aare Sheu Sagari anfaniwo ni won muwo ilu Iwo falana gbotie baba Sokoti oni theaters lamoyin si
oloye sunday igboho is eniyan dada ti o feran iran wa pupo pupo ,yato si awon eni ibi odale won yen , ota yoruba ni awon yen o , , olorun ile yoruba maa ba awon ota wa ja lase olorun oba . ile yoruba agba irorun arowa lorun . lase edumare
Okunrin ti Oba Iwo yi to si wa ni ilu Oyinbo , o soro leyin odun die seyin . O ye ki awon ara iwo ro Oluwo amugbo yen loye .Kini awon arz ilu iwo yi nwo Oloriburuku Oluwo ni eleyi .Oba Fulani ni eleyi o ti gbabode Jihad pelu awon Fulani .E le Rasidi Oluwo kufo lori oye yi o .Omo ale ni .Oba ko to si o
Oluwo kise yoruba fulani ni , mufuti lo sope ki aregbe sola bawon fi sibe , idiniyi ti aregbesola se fa le baba lowo pelu tipatipa , mufuti fulani oluwo fulani , hummmm oluwo wa tun n yan fulani loloye iwo eripe aye yoruba tife baje
Ejowo egbe program jade lori ohun to sele si Soja Dumota to wa ni Iwo. Two World war 2 Memorial Statues were allegedly sold by some people. These statues were given to Iwo since 1945... where are they?
Yoruba o,oro yi ti koja Iwo nikan o Yoruba e ma sun o Oluwo ti fi awon Fulani salatileyin Oluwo ti silekun Sile gbayau Yoruba ti keran mero E wo ni sise o gbogbo Yoruba o
Governor adeleke and paramount king of osun and Nigeria in general were under Islam so people call for government or leaders to intervain is not youth should stand up against them any religion that can't tolerate others no be good religion when d whole world 🌎 become Islam who are you going to preach to
We are okay with the audio, Oga Soskoti. You are interrupting Baba now. We all know it is network problem especially when you are talking but he was hearing.
@@sokotitv1737 My comment was before he licked his phone. His audio was on and he couldn't hear you because of network, so the interruption was obvious. I come with good intention. Thanks
How are you sure that the current oluwo is not a Fulani that grew up in Yoruba land. According to the old man he said it aregbe is the one who handed him over to him and that’s how he met him for the first time. That’s means where he came from is fishy. There are many Fulani in Yoruba land who can speak Yoruba fluently and you will not know he is not Yoruba. Yorubas has to be very careful Fulani are everywhere in the land .
Baba yii lo fi Rashidi joba ilu yii ti baje loju yin ati eyin yin gan an ti baje .oruko yin ko ni pare ninu iwo ati ile yoruba pe eyin le pa iwo re kuro laari yoruba .eku ise baba
Baba ogundokun,may you live long sir. Iwo people should have elect you as king, these man call oluwo, Iwo will never mistake again to elect such a man.
Chief Ogundokun may you live long sir. You're a true son of Ìwọ, a genuine leader. God bless you you sir. Oluwo must respect this honorable baba.
May you live long baba Ogundokun ame. Sokoti that's an excellent job, God bless Sir. You know anytime a dog want to go astray such dog will not listen to the owner. We should leave him alone God will take care of that. Baba emape fun wao agba yin yoo dale o amin.
Gov,Adeleke should dethrone Olowo without further delay Yoruba nation no going back
Why can’t Iwo people dethrone this King. He is disgracing the Yoruba race. Iwo is now a joke. This is too much now
Baba Shokoti Oluwo must go. That's the best way. Best way. Oluwo must go.
BABA OGUNDOKUN, É PE FUN WA. É MA JÈ KI OLUWO KOGUN WO ORILE-EDE YORUBA. ILU IWO O NI BAJE O.. AMIN.
where is governor Adeleke
Dancing and looting
Of cos 😂😂😂😂
End of the time for oluwo, drug taker
Ki Awon Afobaje mura lati ro Oluwo loye abi ko lo si igba .
Governor must be petition for his removal or warning.
Baba ki Emiola Ogun Baba se etiri ohun ti awon omoyoruba so pe kiadaduro niyi baba
Why should Mufti and Oluwo who are criminals be begged to desist from openly committing crimes when we have a government and the Police?
Please Sir, Baba Sokoti stop calling Tahun leader Mufti!!! He lost the Muftihood oif yoruba. Iwo need to take back the Ogun god to its rightful place in the historic palace.
Yoruba nation no going back
Ogbeni Aregbesola caused the problem for Iwo people. He need to dethrone him.
Welcome baba, God bless u
E ro Rasidi Oluwo loye. Let Rasheed Oluwo be dethroned, he's not worth to be a king.,a disgraced king.
If you like call giveenor Adeleke from now till tomorrow he will pay dead ear to the issues in Iwo, because if he does ut may affect his election for second tenure.. but i can tell you boldly if he is elected for second term,he wilk aurely address these issues ..
and that's how you build a watch!!
Why will baba be given him money? For what? Baba is old, baba already spent his money before he became king. Why will be baba be feeding him .
Kí àwọn ọmọ ìwo, àwọn ọmọ Ọsun State, Ọsun state Government, gbogbo ọmọ Yorùbá àti ìjọba Nigeria dìde sí ọrọ Mufti Taun Ìwo àti Oluwo kí ó tó di Boko Haram mi o, bí Boko Haram na ṣe bẹ̀rẹ̀ re o
Governor Adeleke Ademola, ejowo ebawa pana ti oluwo nda ti ofe jo ile Yoruba
Haaa, ỌBA ABIMBOLA, CONTINUE TO REST ON, A TRUE AND RESPECTED OBA OF ÌWỌ AND YORUBA LAND.
uuuuuuhhhhhh emo re oooo ni olu owo , eyin ara iwo , eje yaa kesi olorun iwo dada , emo ti woo iwo , etete gbe igbese , ki ilu to damo , kia kia .
Tell your camera men to adjust now
Network is bad
He can hear you calling him, Network is bad
Oloun lo mu gbogbo yin. Eyin le fi amugbo j'oba apapandodo te yan Eni toba to si je. Oju yin ti ja bayi. Aregbesola na ti gba tie. That is the law of karma.
Baba.Ajala tan naa. Eyin na ni e yan oluwo kale . Oro buruku lenu eiye. Bawo ni oba iwo se n'nwe lawani ni ile yoruba. Se larubawa ni o te iwo do ni ? Iwo baba yii naa ni ipinlese rogbodiyan tinbe nile naa .Ti e ko ba fi oselu yan omo ale yii(Rasidi Amugbo) Idamu ati iberu ki o ba ti sele.
Oloribuku ni gbogbo awon afobaje werey ilu iwo...oloribuku ni yin e ti gba owo lowo amugbo oba werey.
I thought he was imposed on them by the governor of that time?
Gomina adeleke mu oloriburuku oba oofoo Emer iwo yi nitori ki se ijo nukan ni awon ara ilu fi yan gege bi gomina
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa ❤
Leave oluwo alone
Gomina adeleke yen dindinrin ni ohun lo ye ki o mu Omo okunrin amugboo Emer iwo yi ise wo ni gomina adeleke se fun iwo gan
sugbon enu baba yi ko ka oluwo naa , eni ti oti yaawo patapata .
Baba Ogundokun,e pe gbogbo awon to ba ye ke pe mora lori oro you.Ke mo be se mayo Oluwo ko to peju,ile iwo ile Yoruba Nation ni o.
Baba Ogundokun e pe Are BHT,Gomina Adeleke ati Ooni of Ife pelu awon Oba ile Yoruba to ku.
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa❤
Oda ran ni omo okunrin to pe ara re ni oba yi won hun fi esin Bo ju ni hooo, aje ni gbe gba emi ele mi ni omo kurin yi ati awon we re ele sin ja gi di ja gan.
Baba Sokoti ekise omobibi ilu Iwo awatiaje omo ilu Iwo ni amo oun ti sele ni igba ti awon baba Ogundokun wani ipo pataki ninu ijoba Aare Sheu Sagari anfaniwo ni won muwo ilu Iwo falana gbotie baba Sokoti oni theaters lamoyin si
oloye sunday igboho is eniyan dada ti o feran iran wa pupo pupo ,yato si awon eni ibi odale won yen , ota yoruba ni awon yen o , , olorun ile yoruba maa ba awon ota wa ja lase olorun oba . ile yoruba agba irorun arowa lorun . lase edumare
Let the state governor reduce his daily dancing so that he can think the good things he will do to Iwo people
Okunrin ti Oba Iwo yi to si wa ni ilu Oyinbo , o soro leyin odun die seyin .
O ye ki awon ara iwo ro Oluwo amugbo yen loye .Kini awon arz ilu iwo yi nwo
Oloriburuku Oluwo ni eleyi .Oba Fulani ni eleyi o ti gbabode Jihad pelu awon Fulani .E le Rasidi Oluwo kufo lori oye yi o .Omo ale ni .Oba ko to si o
Oluwo kise yoruba fulani ni , mufuti lo sope ki aregbe sola bawon fi sibe , idiniyi ti aregbesola se fa le baba lowo pelu tipatipa , mufuti fulani oluwo fulani , hummmm oluwo wa tun n yan fulani loloye iwo eripe aye yoruba tife baje
baba sokoti eseun pupo , olorun awa pelu yin o
Ejowo egbe program jade lori ohun to sele si Soja Dumota to wa ni Iwo. Two World war 2 Memorial Statues were allegedly sold by some people. These statues were given to Iwo since 1945... where are they?
Yoruba o,oro yi ti koja Iwo nikan o
Yoruba e ma sun o
Oluwo ti fi awon Fulani salatileyin
Oluwo ti silekun Sile gbayau
Yoruba ti keran mero
E wo ni sise o gbogbo Yoruba o
Governor adeleke and paramount king of osun and Nigeria in general were under Islam so people call for government or leaders to intervain is not youth should stand up against them any religion that can't tolerate others no be good religion when d whole world 🌎 become Islam who are you going to preach to
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa
We are okay with the audio, Oga Soskoti. You are interrupting Baba now. We all know it is network problem especially when you are talking but he was hearing.
Must I allow everybody to listen his private discussion? I know what I am doing, what he is saying got nothing to do with our discussion. Thanks
@@sokotitv1737 My comment was before he licked his phone. His audio was on and he couldn't hear you because of network, so the interruption was obvious. I come with good intention. Thanks
Ogundokun Iwo lo fa wahala na
Dis sokoti man is using baba to gain sheap popularity after living film industry. Who is Sokoti to Oluwo?
Shokoti TV .AMUGBO ni rasaki olu iwo.Solution final ni,wipe ki won o roo loye,kii se tuntun .ki ENI to to KO GBA ipo OBA IWO.
How are you sure that the current oluwo is not a Fulani that grew up in Yoruba land. According to the old man he said it aregbe is the one who handed him over to him and that’s how he met him for the first time. That’s means where he came from is fishy. There are many Fulani in Yoruba land who can speak Yoruba fluently and you will not know he is not Yoruba. Yorubas has to be very careful Fulani are everywhere in the land .
Oni yeye ni sokoti alatenuje olojukokoro
Kí niìdí?
I can feed your father
What did sokoti say that was wrong. You are not serious
O ma ale ni e sokoti is a good person
Oloriburuku omo ale. Gbogbo yin lẹ ma sofo kuro nilẹ Yoruba. Asiri yin ti tun, Ride on baba Sokoti
Rubbish
Kangunkangun yoo kangun sibi kan loro oluwo. Ejeki ogun esin bere tiiyoo yo owo oluwo lawo.
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa ❤
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa
Leave oluwo alone
Ogundokun Iwo lo fa wahala na
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa
Ogundokun Iwo lo fa wahala wa
Ogundokun Iwo lo fa wahala
Ogundokun Iwo lo fa wahala
Leave oluwo alone
Oluwo is amugbo, ofo alamu ni. And you know it!!