Alfa Imam gba iyawo Oba ni ilu Ogbomosho

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 8. 07. 2024
  • Eemo sele ni ile yoruba bi imam se gba iyawo Oba alade
    #isese #ogbomosho #africa #imam #oba

Komentáře • 117

  • @adeyemiadams839
    @adeyemiadams839 Před 15 dny +33

    I am a fervent Christian and an Elite Prince in Ekiti. And I can boldly say that any King that kneels down to a religious leader is NOT fit to be king.

  • @monisolarahman762
    @monisolarahman762 Před 15 dny +7

    Tani Olorun,e seun,awon oba agba Yahoo Lani Nile Yoruba,opo ninu won ko mo iyi ati itumo Ori apere ti won wa 😢😢😢

  • @makokin21
    @makokin21 Před 15 dny +10

    Se oba niyen ni tabi baale, that is good for those kings,they had betrayed the Yorubas,we should not pity them.

  • @teejay9674
    @teejay9674 Před 15 dny +21

    Se oba ni eleyi sha. E wo bi o se nsoro bi Eru

  • @Foluxbaby1
    @Foluxbaby1 Před 15 dny +5

    Late Oonirisa oba okunade sijuwade and iku babayeye alafin oyo were the last real kings we had in Yoruba land , the only remaining real king is adimula owa obokun of ijesa land aside the trio, the remaining are gbewudani kings.

  • @Eniola-px1px
    @Eniola-px1px Před 15 dny +8

    Yoruba ti se sin ajoji de ibi esin ba yi hooo

  • @adeonaolafunke4649
    @adeonaolafunke4649 Před 15 dny +8

    Tani Olorun, eleyi gbenu tan ooo

  • @agboolatunde5631
    @agboolatunde5631 Před 15 dny +12

    Its a shame to yoruba land. But at the same time these kings most of dem were raised with isl*m or Christnty while growing up,and its very tough to change ones former belief. So cognitive dissonance would worry them. Islam and Christnty uses fear. But these kings lack’s knowledge on how important our culture and traditions are.

  • @josephmaito213
    @josephmaito213 Před 15 dny +5

    Awon oponu oba

  • @goldtvwalegold8616
    @goldtvwalegold8616 Před 15 dny +9

    Awon Oba yeye, awon Oba oloselu

  • @Eniola-px1px
    @Eniola-px1px Před 15 dny +5

    Oba hun wa owo ojiji, ni eleyi to hun fa abuku fun won, ise agbe ni ki oba mu oju to ki a pon le fi pada si ara won

  • @oluomopeter2936
    @oluomopeter2936 Před 15 dny +14

    All the religion has brought taboo to yoruba land 😂😂😂😂😂😂

  • @okunadeadigun7401
    @okunadeadigun7401 Před 15 dny +4

    Kuli alau fun eni toti ku ejiogbe fun awa tawa laye

  • @israelomos2651
    @israelomos2651 Před 15 dny +6

    That's how Emirate of Iwo will soon be insha'Allah that king is a slave to Imam.😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂why king will stand at back of Oba which means Oba oba Lori ekun 😢😢😢

  • @JaxDad1
    @JaxDad1 Před 15 dny +2

    Tani Olohun una no go kee me oh . Ọba ilu mu ọti gbagbe Ade Kẹ 😆 🤣 😂 😊. Ọba ki jẹun ni ita kẹ?? Emir Oluwo so agabada kọ jẹ rice ati Chicken

  • @Oloriebi21
    @Oloriebi21 Před 15 dny +2

    :To be candid, this guy (Tani Olorun) always make a lot of senses. Kudos to you. Keep it up. Please Ajanasi, don't relent you are awesome. Nigeria they hate thee, UK.

  • @davidapalowo8985
    @davidapalowo8985 Před 15 dny +3

    Tani Ọlọhun you are a great man i laugh tired

  • @dbanjjoseph2137
    @dbanjjoseph2137 Před 12 dny

    Se oba ni awon eleyi tabi eru allahu

  • @adexadexd1
    @adexadexd1 Před 15 dny +6

    Oba sumondere.

  • @AjagbeIsa
    @AjagbeIsa Před 10 dny

    Tani olohun, Pele masunkun mo 😢😢😢

  • @goldtvwalegold8616
    @goldtvwalegold8616 Před 15 dny +5

    Esin ajoji ni won fe fi pa asa ati ise wa re

  • @IfatumoIyanda
    @IfatumoIyanda Před 15 dny +1

    Oba lamidi adeyemi alaafin of oyo orun re re oooo. Koni gba radarada

  • @user-iq3fj1lx7r
    @user-iq3fj1lx7r Před 14 dny

    Awon oba yahoo ni gbogbo won ni Saudi se lman ni agbara lo oba saudi ni

  • @falohunibrahim633
    @falohunibrahim633 Před 11 dny

    oba ko ni iyen oba rada rada ni ,

  • @IfatumoIyanda
    @IfatumoIyanda Před 15 dny +3

    Aye oba eleyi ti ta set awon dindinrin

  • @nathaolu5600
    @nathaolu5600 Před 15 dny +4

    Ogunwusi is not worth to be king
    Adeboye ti sise
    Awon musulumi wonyi oro won ti su mi.

  • @abiolabasirutajudeen2407
    @abiolabasirutajudeen2407 Před 15 dny +1

    Awon
    Oponu oba
    😢🤣😂🤣

  • @Eniola-px1px
    @Eniola-px1px Před 15 dny +2

    Ki awon oba pa da si idi ise ogbin, ki ebi fi ku ro ni ilu, ki awon oba fi pada ni yi ni inu ilu pada.

  • @seedofsalvationministry

    Oba ba Lori ohun gbogboo

  • @racheldavis2554
    @racheldavis2554 Před 15 dny +3

    Oga o 😢

  • @muritalaabiodunsodiq7038
    @muritalaabiodunsodiq7038 Před 15 dny +5

    Eku eto sir

  • @omotoshoolawunmi
    @omotoshoolawunmi Před 10 dny

    Se oba Le yi

  • @Eniola-px1px
    @Eniola-px1px Před 15 dny +4

    Ki ni a hun fa ni ti esin ajoji se fun wa, ko ja wi pe iro ati jibiti ni esin ajoji ko wa fun wa, omo ale wa po bi re re.

  • @horlahinksj7644
    @horlahinksj7644 Před 14 dny

    Thanks bàbá. More harms to come jàre 😢😢.

  • @abimbolaidowu9532
    @abimbolaidowu9532 Před 15 dny +1

    The king 👑👑👑 in Yoruba is the head of religion in the Yoruba land. From Muslims and Christians and traditional religion.. because the king 👑 in Yoruba land has no religion.king is above anyone

  • @FashinaSaka
    @FashinaSaka Před 15 dny +1

    Awon oba ye gangan ni won ba aye ara won je

  • @aderojuaderoju1752
    @aderojuaderoju1752 Před 14 dny

    igberaga po fun awon Imam ati Alfa
    eyo enikan pere yi o maape arare ni awa

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 Před 15 dny +2

    Imam TOILET 😂🤣😄😂🤣😄

  • @binaryworlddhopeengine451

    Lemanmu do iyawo oba😂😂

    • @Emiola_1
      @Emiola_1 Před 15 dny +1

      😂😂

    • @binaryworlddhopeengine451
      @binaryworlddhopeengine451 Před 15 dny +1

      @@Emiola_1 😂😂

    • @akinsolajoseph5391
      @akinsolajoseph5391 Před 15 dny +1

      😂😂😂😂 ẹni dòní láyà o jẹ bi 😅😅😅😅Aya yin ni kẹ bawi 😅😅😅😅😅😅oba yeye😅

    • @akinsolajoseph5391
      @akinsolajoseph5391 Před 15 dny

      😂😂😂😂 ẹni dòní láyà o jẹ bi 😅😅😅😅Aya yin ni kẹ bawi 😅😅😅😅😅😅oba yeye😅

    • @binaryworlddhopeengine451
      @binaryworlddhopeengine451 Před 14 dny +1

      @@akinsolajoseph5391 imanmu mu omu iyawo oba 😂😂

  • @AdekunleZainab-yt7tk
    @AdekunleZainab-yt7tk Před 4 dny

    Rederede 😎

  • @adegbitestephen
    @adegbitestephen Před 14 dny +1

    What a pity

  • @olatunjibabatunde998
    @olatunjibabatunde998 Před 15 dny +2

    Eleriibu oba

  • @WeAreTrueAfrican
    @WeAreTrueAfrican Před 15 dny +4

    Oba yeye he not oba

  • @sunandblackness1429
    @sunandblackness1429 Před 15 dny

    Thank You Sir
    Ogbo aAto

  • @oloyedeabiodun6989
    @oloyedeabiodun6989 Před 15 dny +1

    Yoruba bo, won ni Amukun eru e wo, oni oke le n wo eo wo isale, Eyin Oba Alade, odowo yin o.

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp

    RADARADA

  • @omofemy4479
    @omofemy4479 Před 15 dny +3

    This man no be oba abeg,na baale him be

    • @Eniola-px1px
      @Eniola-px1px Před 15 dny +3

      If it’s baale, you don’t know that they are use religion to disrespect our land, they called us eru larubawa

  • @opeoluwasunday3062
    @opeoluwasunday3062 Před 15 dny +1

    Ki olodumare ma abo rẹ bo ọọ lọla awọn irumalẹ asẹ wa

  • @Eniola-px1px
    @Eniola-px1px Před 15 dny +3

    Yoruba done enter one chance

    • @binaryworlddhopeengine451
      @binaryworlddhopeengine451 Před 14 dny

      Its neo-colonialism, it's among what they used to conquered and created Nigeria, other Africa countries

  • @oyebanjiayodeji8877
    @oyebanjiayodeji8877 Před 15 dny +1

    This video should be pisted on your Facebook page ..

  • @akinwunmiolumide7590
    @akinwunmiolumide7590 Před 14 dny

    HMM INFACT

  • @AjagbeIsa
    @AjagbeIsa Před 10 dny

    Se iwonikan ni Yoruba ni

  • @OmoIrunmole29
    @OmoIrunmole29 Před 15 dny

    Oba werey wo nie omo Eru keru abilala lenu

  • @user-qz1xz6my7l
    @user-qz1xz6my7l Před 15 dny +1

    Kini iyawo oba wade odo Alfa

  • @bummy1532
    @bummy1532 Před 15 dny +2

    The woman must be….i don’t know 😅

  • @deobisi8483
    @deobisi8483 Před 15 dny

    Awon oba fe wo alijannah loje ki won won maa sa si abe imam awon lemonu si ni o mu kokoro alijanna lowo😂😂

  • @odunladeadegoke8060
    @odunladeadegoke8060 Před 15 dny

    Tani olohun you want to kill me with laugh o, oba mu oti gbagbe Ade, it will soon happen

  • @omofemy4479
    @omofemy4479 Před 15 dny

    Normal normal yoruba people like eye service

  • @FashinaSaka
    @FashinaSaka Před 15 dny

    Se ko si magun ni ilu ye ni ni aye ati jo gbogbo eni ti o ba do iyawo oba ni igba ye won ma ku ni😂

  • @oe6526
    @oe6526 Před 15 dny +2

    But ki lamidi to ku, agbo pe awon olorin kan gba iyawo re now?

  • @falohunibrahim633
    @falohunibrahim633 Před 11 dny

    ti alufa kan ba dan iru e wo si sa ka ni ma da gbogbo irin ajo ila aye ru pa ta pa ta , ma ko e yin si ara ilu

  • @FashinaSaka
    @FashinaSaka Před 15 dny

    Ogbo ato asure iwori wofun ifa adori aya akire mawimawi ni ti eye awoko olu eja ki lu iwo

  • @user-mj6jy8rn8h
    @user-mj6jy8rn8h Před 15 dny +1

    Ko seni tole do iyawo Oba laye atijo,politicians loba tani laye oni.

  • @Sulaimonola-yr6ml
    @Sulaimonola-yr6ml Před 15 dny +1

    I am not sure he his a real king... maybe Baale. Bcos king no dey talk like this

  • @Babatunde2424
    @Babatunde2424 Před 15 dny +2

    It's embarrassing

  • @user-qz1xz6my7l
    @user-qz1xz6my7l Před 15 dny

    Seranu lowadebe nii tabi ,se otuu nowonfun tabi alagbere niyen noo nii .ororadarada.

  • @geraldjohn1588
    @geraldjohn1588 Před 15 dny +1

    Nonesense things. Iru iran rada rada elesin wo ni awon ara bi yii naa? Won kan nfi esin ba ilu je kaakiri dipo ki won maa tun ilu şe. Pala pala ilu apala. Ki Imam maa fi owo l'ale lori odidi Oba ilu. O ma şe ooo.

  • @okikiakinnibosun4953
    @okikiakinnibosun4953 Před 15 dny +1

    Ogbenutan

  • @FashinaSaka
    @FashinaSaka Před 15 dny

    Awon elesin mejeji ni won ba asa wa je nitori gbogbo ikan ti o je asa wa ni awon elesin mejeji ta ko

  • @JimohRidwanullah
    @JimohRidwanullah Před 14 dny +1

    Hunnnn...
    Many things are wrong somewhere...
    We need to know the difference between the language and religion... Otherwise we'll definitely be confused....
    Who sent ifa, irunmole... and what's the evidence!

    • @JimohRidwanullah
      @JimohRidwanullah Před 14 dny

      Being the Yoruba didn't lead us to be worshipping ifa, sango, egungun....
      If I may ask!
      what's their source?...
      That related to Olodumare ...
      I want any the response?

    • @binaryworlddhopeengine451
      @binaryworlddhopeengine451 Před 14 dny

      All religions are created from cultures, culture can be defined as the way of life..., the concept of the Abrahamic religions:Judaism,Christianity and Islam was copied from Africa..., Christianity was copied from Judaism and Islam copied from Christianity, Islam is the religion made for only desert Arabia, they spread by conquering people and deceitful.
      In conclusion, Ifa is older than the three Abrahamic religions. Ire o

  • @israelomos2651
    @israelomos2651 Před 15 dny

    😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂

  • @abbey923
    @abbey923 Před 15 dny +1

    6:04 Concerning the yìgì, I’ve posted the below before:
    Nikkah (Islamic “marriage”) is not something sacred unlike how marriage is regarded in most religions and cultures.
    It is, in literal and practical terms, a contract that makes a sexual relationship between a couple permissible. Its root is the verb, “nakaha” which means to have sexual intercourse.
    There are also different types of Nikkah. And disagreement over them is a major cause of sectarian divisions in Islam.

  • @AncientHebrewNeverDied

    Why didn't the king just marry another wife? Women finish for the domain or Yorubaland? Unless there was no intercourse btw the Imam and woman, that is, the Imam only took away the woman he gave the King and then returned her when the King did his bidding.

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 Před 15 dny +2

    Ooni Ogunwusi Ojaja III is even worse than this Oba that the Imam took his wife. Ooni Adeyeye Ogunwusi is the worst Oba so far in Yorubaland. Ooni has degraded our Culture & Traditions so many times

    • @loantha2996
      @loantha2996 Před 15 dny

      Crookcrookdie

    • @victorabayomi2995
      @victorabayomi2995 Před 14 dny

      Which culture of yours did Ooni desecrate? You just wanted to listen to your voice. Has Ooni Ogunwusi not been living to expectations. I need more clarifications.

  • @user-id3yf2kw7w
    @user-id3yf2kw7w Před 15 dny

    I'm from a royal family, most of this Oba new generation has never been choosing as in iwase. Now, power to be chosen Oba now for political purposes.
    *Awon olosi oba ton de ade palli, Oba otilekun mori ba garri ja*

  • @loantha2996
    @loantha2996 Před 15 dny

    They're both mohamedans

  • @habeebadewuyi4263
    @habeebadewuyi4263 Před 14 dny

    You need to show maturity with your talk, don't call names, they will arrest you again and nothing will happen. Be careful, you can talk without mentioning any name.

  • @Foluxbaby1
    @Foluxbaby1 Před 15 dny

    This oba self is a coward, ASE LOBA N PA, OBA KII DABA

  • @user-kk9vx6tb6j
    @user-kk9vx6tb6j Před 15 dny

    Eleyi o ki nse oba gidi Tani olorun don’t speak for this weak king

  • @oe6526
    @oe6526 Před 15 dny +1

    "Ki awon irunmole gbayin"
    Soronu?
    Irunmole wo lo fe gbayin nibi oju 👁 lade yi?
    Awon irunmole ti da mo! If it was possible for the irunmole to return, they would be politicians
    taniolohun go and get some gombo marks or pele on your face to save your culture.
    How many oba whom ifa picked have tribal marks?
    Melo ninu omoba lo ko ila (mark)?
    So what culture exactly are you whining about?

  • @Monsuurajamuabdulrofih

    Taani olohun or what is your name
    U don start again A bi?
    Hmmm Aanu re n semi
    U don't no anything than
    The issue related to ISLAM

  • @gasteeroy8518
    @gasteeroy8518 Před 15 dny +5

    Oba gandi lost his respect to immam yinusa since the day he knelt down for pastor adeboye. Immam is the head of Muslim and adeboye is the head of Christian

    • @sammygy30
      @sammygy30 Před 15 dny +1

      Ur wrong,the picture you saw there was a blessing from Adeboye to allow him to n be king. I've you forgotten he was a redeemed pastor. Please get fact before saying anything. Adeboye is not head of CAN. Please do your findings.

    • @loantha2996
      @loantha2996 Před 15 dny

      The king owns the town

  • @userOlowu
    @userOlowu Před 15 dny +2

    Imagine the bastard saying trash in front of Yoruba king ,in the olding days you won't even dare try it with bale talk less of a king,aje even me thats not from royal family no imam dare try that shit with my woman aje orulalaa.