ORÍKÌ ÌLÚ ÒGBÓMỌ̀ṢỌ́ (Eulogy Of Ògbómọ̀ṣọ́)

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 29. 08. 2024
  • Ògbómoṣó Ajílété
    Ibi wón gbé ń je'kà k'àn tó mù'kọ yangan le
    Ògbómoṣó ìlú ọ̀lẹ 'ò gbe
    Akíkanjú ló ń gbé be
    Ṣebi ògbórí ẹlẹ́mọ̀ṣọ́
    N'La sọ d'Ògbómoṣó
    Ògbómọjúkun ògbo Ṣẹ̀gi ṣẹ̀gi
    Ògbó isu tí ń j'iyan
    Ọmọ ògbólóògbó
    Ibi wón tí n fògbó kan'ògbó
    Dùǹdú f'ọ̀rọ̀ gbogbo ṣ'àpamọ́ra
    Wón na Ògbómoṣó lóde kò délé wí
    Ó dé'lé ó rò f'óògùn
    Ògùn ló lọjọ́ kan ìpónjú
    Orí ẹni lólọjọ́ gbogbo
    Ọmó apebi mó'nú
    Ajílété ń ṣe bí ayo
    Ògbómoṣó kọ olè
    Ó kọ ọ̀lẹ,ó kọ ìmẹ́lẹ́, ó kọ agbéraga......
    An Eulogy Of Ogbomosho.
    The town of seasoned warriors.
    A town filled with dedicated and great people.
    A true ogbomosho indigent doesn't steal, rather, he prefers to eat from the works of his hand, and he depises pride.
    An ogbomosho indigent has a deep and hard heart, he doesn't accept defeat, he's fearless.

Komentáře • 15