ẸYIN OLOṢELU NAIJIRIA, ẸYIN NAA ẸẸ SI ṢE BII AWỌN ARA UK

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 9. 07. 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
  • Zábava

Komentáře • 24

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff6458 Před 16 dny +7

    Mama Alaroye you are too much

  • @user-fp1pz2gg8x
    @user-fp1pz2gg8x Před 15 dny +1

    YES OO LABOUR WINNING EVERYONE LOVE HIM ❤️😍💖❣️

  • @adeonaolafunke4649
    @adeonaolafunke4649 Před 16 dny +3

    God bless you ma

  • @samsonolayiwole6398
    @samsonolayiwole6398 Před 16 dny +3

    The problem is that our politicians are they listen to news

  • @victordare3299
    @victordare3299 Před 16 dny +7

    Mo ṣe sadankata agbekale rẹ. Ọlọ́run Olódùmarè yóò máa ràn ó lọwọ gidigidi. Kódà mo fe ki Yoruba Àtàtà dá ọ lola. Ó mọ ọrọ gbé kalẹ, ohun rẹ sì dùn mọran-in mọran-in. Lọjọ kan, Ọlọ́run oga ògo yóò lọ ọrọ ati agbekale rẹ láti ṣe àtúnṣe tí ipa ọ̀nà sójà tàbí Oloselu alágbára kan kò lè ṣe. Fi ọ̀rọ̀ yìí pamọ. Gbàdúrà pelu mi. Jẹ ká wo ohun tí Ọlọ́run lè ṣe. Ìyàlẹ́nu lo máa jẹ bí oko Dáfídì tó pá tí Golayati. It is well with you and Alaroye.

  • @adeonaolafunke4649
    @adeonaolafunke4649 Před 16 dny +2

    Geskia

  • @graceoladejo6073
    @graceoladejo6073 Před 16 dny +1

    E je ki won se naijiria bi won se fe ki won le ko oro ti won un ko jo lo si orun

  • @oluwoleebenezert-qq2be
    @oluwoleebenezert-qq2be Před 16 dny +3

    Ko si "emi lo kan" ko si "irreparable severe damage tee ba gbe certificate mi jade" O ti pe gaan ti Tinubu ti ba Nigeria je pelu corruption ati iwa odaran ponbele. Tinubu gaan ni Baba ati grandfather awon ehanna oloselu Nigeria. O maa pe gaan ni ki Nigeria to roju!!!

  • @lukmonolamilekan8616
    @lukmonolamilekan8616 Před 16 dny +1

    But with all this they'll still not do so unless if Nigeria comes out with revolution

  • @user-fp1pz2gg8x
    @user-fp1pz2gg8x Před 15 dny +1

    E SÈ IYAMI OWUN NI AWON OYINBO SE PE WA NI ERAKO

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 Před 13 dny

    Esu ni oludari ibo fun awon omo orilede Nigeria

  • @africanoriginal380
    @africanoriginal380 Před 16 dny +2

    Ohun t'o fi ri bayi ni pe, awon olori Nigeria nse oso, aje ati oogun buruku ni. Won nba esu je, nitori bee, awon emi okunkun l'o dari i won. Awon ti won npe ra won ni Christian kan nfi se bojuboju ni. Awo kanna jo ni gbogbo won, esu de l'oga won. Isejoba ati isakoso inaki.

  • @agbekeaiyedun7107
    @agbekeaiyedun7107 Před 16 dny +1

    Alaroye it can never happen in Nigeria of today cos genesis of Nigeria politics was Lie nd rigging nd dey don't have passion for Nigeria masses

  • @user-yw3iy7iu6w
    @user-yw3iy7iu6w Před 16 dny +1

    But awon U.K. na ni koje ki naijiria roju.

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681 Před 16 dny +3

    IYA ALAROYE ENIA MI NI YIN LOJOKOJO OLORUN O MI GBA OHUN NA LENU YIN YIO SIA JUSE FUN YIN GBOSA GBOSA GBOSA FIN YIN

  • @timothywale8055
    @timothywale8055 Před 16 dny +3

    Iya Alaroye , se eyin koma wipe Olorun lo da awon oyinbo ni ?

    • @ibraheemabiodun2114
      @ibraheemabiodun2114 Před 16 dny +2

      Talo da awon Omo Nigeria?

    • @sakenatafolabi8666
      @sakenatafolabi8666 Před 16 dny

      😂😂😂

    • @roselinebolanle9404
      @roselinebolanle9404 Před 16 dny +1

      Ole lawon Oselu Nigeria,Awon ojelu ti won nperawon loselu, won se ilu Titi Nigeria nwa backward si loojoojumo sugbon won rii ro nitoripe eranko niwon🐎🧑🏾‍🦯 ise lawon oyinbo nse with full monitoring atipe ko si eniti o koja ofin won,

    • @roselinebolanle9404
      @roselinebolanle9404 Před 16 dny +2

      Taloda awa eniyan Dudu o?😂 olorun loda gbogbo wa ,sugbon eniyan Dudu wa greedy ni😂won je alainitelorun bi eranko ni won se nwuwa , Asiwere won nko oro jo👧🏾

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b Před 16 dny +2

    President Nigeria ati government's there all robbery and craze from the top to bottom there all robbery awon Oleselu ole ni gbogbo won lati tori president to fi isale ole ni won ise wo won se ti won ri ati iyawo president ati president fun ra re

  • @sulele7666
    @sulele7666 Před 15 dny

    Diedie ni, awon naa ti gba ibi ti a wa yi koja. Olohun dakun ran wa l'owo.