EEGUN ALAPANSASNPA NI ILU IBADAN

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 16. 02. 2021
  • Àwọn ohun pàtàkì tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa Eégún Alápáńsánpá ní ẹ ó rìí wò níbí.

Komentáře • 9

  • @giveway...6838
    @giveway...6838 Před rokem +2

    iro buruku radarada tepa fun rayin... Eeniyan nko lowa ninu e, ten ran aso fun..... Ogun ko Ogun ni.... Eri àwon Boko Haramu mu... Àwon ole eri won mu.... Koma da ki eniyan ma ni Olorun ninu aiye Ooooooo......

  • @bolarindetoba1061
    @bolarindetoba1061 Před 10 měsíci +1

    E da egungun yi pada si ibi ti e ti gbe o. Egungun ilu mi ni o.

  • @igeadubi5883
    @igeadubi5883 Před 3 lety +1

    Alapansanpa ni oba egun oloore

  • @sheyiadesuyi5822
    @sheyiadesuyi5822 Před 3 lety +1

    Eku eto Ile oduduwa agbe wa oooo, yoruba Nation now,

  • @olalerelukman9120
    @olalerelukman9120 Před rokem +1

    Egungun ile baba mi kobomoje orowusi