OONI OJAJA KEJI NI KI WON SE ARAKUNRIN TI O PE ARA E NI ỌMỌ OUN JẸJẸ,KI ẸNIKẸNI MA SE DUN KOKO MỌ

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 10. 06. 2024
  • ALUKORO ATI AGBENU SỌ FUN KABIESI OONI TI ILE IFE,OGBENI MOSES TI FI DA TBOY ARAKUNRIN TI O PE ARA E NI OMO OONIRISA TI O WA NI IPAMỌ loju wipe kabiesi ko ní okan lati fi ija jẹ nitori wipe o han wipe arakunrin oun nilo iranlọwọ ni
    Aafin Ooni ni ọgbẹni Moses ti sọrọ yii nigbati o n gba àlejò Arakunrin Taiwo Adekomaya ti o pe ara e ni ọmọ Ọọni ninu fónrán kan ti o da awuyewuye silẹ nipa Ooni Risa lori CZcams... Eleyiti o mu ọpọlọpọ gbagbọ nitotọ wipe Kabiesi ni ọmọ Ọkunrin kan ni ipamọ lootọ
    Arakunrin Taiwo eniti o gba ni ọpọlọpọ àsìkò lati yoju Si aafin nitori eru wipe ko mọ oun ti oun yíò ba,ni pàápàá ti awọn iwe Iroyin kan ti fi wẹlọ wipe awọn olopa abẹnu n waa,ri oju rere Kabiesi gba
    Gegebi Olusiro Kabiesi se wí baba ni ipinu nla fún ùn lati yí ìgbésí ayé e pada sí rere,gegebi won se ni kabiesi sọ,won ni iranlọwọ ni awọn Woye wipe arakunrin oun nilo nitori naa kabiesi pàṣẹ wipe ki won ma tun fi ọrọ a n gbe ni lọ sí ọdọ olópàá di kun erun e
    Nitori èyí le bẹ Igi di ona ọjọ iwaju rere rẹ ati wipe káábíèsí pinu lati sure fún ùn pẹlu ki Atunbotan iwa ti o Wu naa ma baa ni ipá burú lori e lojo iwaju
    #entertainment
    #ooniofife
    #ooniofifewives
    #oonichildren
    #yorubalanguage
    #yorubanation
    #culture #entertainment #nigerianentertainment #dna #fashion #mohbad

Komentáře •