Mo kí yin daada, Baba. Eledua ama fún yín ṣe. Àṣẹ. Ọrọ kan rumi loju. Irawọ Gemini ni mi. Mo sì sakiyesi pe kò sí lára àwọn tí ẹka fún irawọ omi. Sugbọn wọn ti sọ funmi bi ona meji pe ọmọ omi ni mi. Kíní iyatọ t'owa l'arin ẹni toni irawọ omi ati ọmọ omi? Ẹsẹ, modupe.
You can be irawo ina,afefe, or erupe and be omo omi, omo omi can also be referred to EMERE OMO OMI, IRAWO OMI IS LIKE OTHER IRAWO , MOST OF THEM ARE OMO OMI
Next term try to switch the underground sound off to hear what you're saying . Thank you
thanks sir
Jah blessing sir🙇💕
amin
Thank you for this ,. Nw I understand my self beta ,. All what you said is what I been doing ,. I will take to d warning,. Omi a gbe wa ooo
Wonderful!
Why the underground noise.
Thank you sir olorun abami dupe fun yin oo Amin
Aaamin
Thanks for the update sir
UWC
Pls sir, is it only catfish that's taboo for CANCER 🦀 or all the fish?
Yessss
We are proud of you 💖
thanks
9:04 u are right 💯
Mo kí yin daada, Baba. Eledua ama fún yín ṣe. Àṣẹ. Ọrọ kan rumi loju. Irawọ Gemini ni mi. Mo sì sakiyesi pe kò sí lára àwọn tí ẹka fún irawọ omi. Sugbọn wọn ti sọ funmi bi ona meji pe ọmọ omi ni mi. Kíní iyatọ t'owa l'arin ẹni toni irawọ omi ati ọmọ omi? Ẹsẹ, modupe.
O leje irawo Afefe, ki o je omo emere elegbe omi spiritualy
@@IGBAGBO_72. Ẹse, mo'dupẹ. Ayé o ni p'oun mọn agogo yín. Àṣẹ.
Sir , can a irawo erupe girl date a irawo afefe boy with the intention of it leading to Marriage?
👍
Sir!,,,the June 21 of Cancer star,,, are they having the same do's nd don't sir?,,, Thanks nd weldone sir,,God bless you immensely sir,,,,
its similar
Pls can you talk about Irawo ile.
check the video on my CZcams
Pls sir what is the tittle?
Ichê irawa Omi
O wanbe
What about us that are born in December,
What date.
Sir I greet you for a good job. You haven't Analyse 'eewo fun irawo Ile/erupe.
watch carefuly, its there
otito oro
Pls sir kindly reduce the drum on yur background so that yur audio can more louder than the drum
yes sir
Am Dec 22 pls sir my fiance is October 13 are we good to go
Yes you go on you're Ina while your partner is Afefe
Sir,pls what is/are difference between omo omi and irawo omi
You can be irawo ina,afefe, or erupe and be omo omi, omo omi can also be referred to EMERE OMO OMI, IRAWO OMI IS LIKE OTHER IRAWO , MOST OF THEM ARE OMO OMI
@@IGBAGBO_72. thank you sir
Bawo leyan se ma mo pe ohun wa ninu epe
E maa wadi lodo awon to mon Nipa re
Sir what about eewo irawo afefe but elegbe omi ni
check my videos
Hello, so we should Not eat Any Fish at all or just catfish??
just cat fish
Sir bawo ni omo irawo Ina Leo ♌🦁 ti won ni ko Maje eja aro
O le je omo elegbe,omo omi
@@IGBAGBO_72. baba..pls mini itumo ati oun ti Ado ide tunmo si?
Kini idi ti Omo mi ki ni ibujoko ni Ile oko ???
Oleje, egbe, Afowofa tabi ogun.....E sewadi lodo awon oni mimon
Pls sir am march18 and Mary July 27 wit 2 kids pls what can I do, and you talk about fish. Se kama je eja Lankan rara ni abi cat fish nkan ni.
cat fish
@@IGBAGBO_72. thanks sir
Hi please I want to know about my spirit husband
Please I want to know what my egbe want from me
@@bosesamuel9771 Bose I will ask them