Yoruba hymn-AIGBAGBO BILA TEMI L’OLUWA/BE GONE UNBELIEVE.

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 7. 09. 2024
  • Verse 1
    Aigbagbo bila temi l’Oluwa,
    O o si dide fun igbala mi
    Ki nsa ma gbadura, On o seranwo
    Gba Krist’ wa lodo mi, Ifoiya kosi.
    Verse 2
    B’ona mi bas u, On l’osa ntomi
    ki nsa gboran sa, On o si pese
    Bi iranlowo eda gbogbo saki
    Oro t’enu Re so y’o bori dandan.
    Verse 3
    Ife t’o nfi han ko nje ki nro pe
    Y’o fi mi sile ninu wahala
    Iranwo ti mo si nri lojojumo
    O nki mi laiya pe; emi o la ja
    Verse 4
    Emi o se kun tori iponju
    Tabi irora? O ti so tele
    Mo m’oro Re p’awon ajogun ‘gbala
    Nwon ko le s’aikoja larin wahala.
    Verse 5
    Eda ko le so kikoro ago
    T’Olugbala mu, k’elese le ye
    Aiye Re tile buru ju temi lo
    Jesus ha le jiya, k’emi si ma sa!

Komentáře • 3