Lateef Adedimeji - Èyí ni bí Túndé Kèlání ṣe sọ mí di Àyìnlá Ọmọwúrà

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 8. 09. 2024
  • Ni lokeṣan fiimu Àyìnlá Ọmọwúrà, ti Alagba Túndé Kèlání, n ya lọwọ niluu Abẹokuta, oríṣiríṣi lo n ṣẹlẹ níbẹ. Ọkan pataki ninu awon òṣèré to kopa ni Lateef Adedimeji. Ojúlówó iṣẹ l'ọkunrin onitiata yii ṣe láti gbé iṣẹ̀dá ìtàn wọ gẹgẹ bi Àyìnlá Ọmọwúrà, bẹẹ ni itan ọhun da lori Àyìnlá Ọmọwúrà ati ilu Ẹgba, paapaa oṣu mẹfa ṣáájú iku ọga olorin Apàlà ọhun, Eégúnmọgají Waheed Àyìnlá.......

Komentáře • 26