NÍTORÍ ÌWỌ́DE TÓ Ń BỌ̀ ÌJỌBA ÀPAPỌ̀ TI Ń TA ÀPÒ ÌRẸSÌ LÓWÓ PỌ́Ọ́KÚ, ÌGBOHO ÒÒṢÀ, ÈSÌ Ọ̀RỌ̀ MAIYEGUN

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 7. 09. 2024
  • ÌRÒYÌN : NÍTORÍ ÌWỌ́DE TÓ FẸ́ WÁYÉ ÌJỌBA ÀPAPỌ̀ TI Ń TA APO ÌRẸSÌ NÍ OWÓ PỌ́Ọ́KU, ÌGBOHO OOSA ESI ORO MAIYEGUN DIARY 30/7/2024

Komentáře • 15

  • @beckyaanu7034
    @beckyaanu7034 Před měsícem +4

    Yoruba Nation no going back

  • @adefolakemiakintuyi9893
    @adefolakemiakintuyi9893 Před měsícem +2

    Mayegun haaaaa o de beru Olorun kilode my brother?

  • @user-gq7oq5uo1j
    @user-gq7oq5uo1j Před měsícem +3

    Maiyegun's diary ọmọ ale

  • @davidadewole4614
    @davidadewole4614 Před měsícem +1

    YORUBA NATION NOW NOW NOW
    YORUBA NATION NO GOING BACK

  • @olufemioshikoya4651
    @olufemioshikoya4651 Před měsícem +2

    OMOKOMO NI MAIYEGUN TIPETIPE. KO LE SE ALAISO ISOKUSO. A GBO WIPE ODUN MOKANLA NI IYA E LOYUN E. SO A SO ISOKUSO. OMO JATIJATI OKO ARUGBO.

  • @uniquebabybabygirl5640
    @uniquebabybabygirl5640 Před měsícem +1

    😂😂😂asake grandma oyinbo o pa mi lerin

  • @mrscpower6200
    @mrscpower6200 Před měsícem +1

    Badero’s family are like that, l know them very well

  • @user-fb7qi5nl1z
    @user-fb7qi5nl1z Před měsícem +1

    Asake E ku eto Yoruba nation no going back

  • @olufemioshikoya4651
    @olufemioshikoya4651 Před měsícem +1

    ORI MAIYEGUN TI GBALE

  • @adekoyamichael6909
    @adekoyamichael6909 Před měsícem +1

    Se owo poku ni ogoji egberun ti won fe apo iresi.
    Se iye ti awon ijoba APC ba apo iresi niyen.
    Ati pe se iresi nikan ni awon omo Nigeria ma a je ni.
    E Jo Ma awon fulani ni won si n dariji wa Jo.
    Won kan n fi wa ta Tete ni ma.

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b Před měsícem +1

    Will want yoruba Nation bad government he is not Good

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b Před měsícem

    Eyin o mo pe president Nigeria ko fe se yoruba Nation nitori iyawo e o fe je iyawo president Nigeria eru le di Olorun oto ni eyan je president oto ni ki Olorun fun e se wo ise owo e na ko ni o fe je president wo iwa na owo le fi de president Nigeria atubotan nko

  • @FolasadeFagbola
    @FolasadeFagbola Před měsícem +1

    Huúuuunnn won o ba ta app rice 'i #10.000 igbawo ni won fi ma je tan? Abi ka pin Nigeria ko onikaluku SE ijoba e Bo de wuu

  • @FolasadeFagbola
    @FolasadeFagbola Před měsícem +1

    Kini isoro awon Yoruba fe GBA lowo Sunday igboho na ?