OLOYE M.O. OGUNMOLA (OTUN OYO ATI OLUDASILE ILE EKO LADIGBOLU GRAMMAR SCHOOL, OYO)

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 6. 05. 2022
  • Èyí jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe pàtàkì lórí Ìtàn ìlú Ọ̀yọ́ àti àwọn ìlànà tí ó rọ̀ mọ́ yíyan Àláàfin, níbi tí a ti ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú Olóyè M.O. ÒGÚNMỌ́LÁ tí wọ́n jẹ́ Ọ̀tún Ọ̀yọ́ àti Olùdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ Ládìgbòlú Grammar School ní ìlú Ọ̀yọ́.
    Ẹ má gbàgbé láti darapọ̀ mọ́ wa lójú òpó CZcams (Subscribe) yìí láti máa gbádùn àwọn ohun Ìṣẹ̀dálẹ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Yorùbá àtàtà.

Komentáře • 30