Is Oro Festival the Solution to Hunger in the country?

Sdílet
Vložit
  • čas přidán 12. 09. 2024
  • Is Oro Festival the Solution to Hunger in the country? What Isese practitioners in Lagos need to know a

Komentáře • 47

  • @fabrowzertv5234
    @fabrowzertv5234 Před měsícem +1

    Eseun pupo baba Adeifa fun oro imoran yii❤❤❤❤

  • @MuyiwaDare
    @MuyiwaDare Před měsícem +1

    Love you Baba Awo Adeifa❤ ❤❤

  • @WasiuRaimi-l2m
    @WasiuRaimi-l2m Před měsícem +1

    My father what does a good evening how is work today sir we want our nation of Yoruba we are indigan of Yoruba Yoruba need to exist in Nigeria we need to assist in Nigeria after we assist in here so we will know what next in our self

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 Před měsícem +2

    Baba Adeifa Iwalesin, please go and tell Tani Olohun to stop defending what is not defendable. People are really angry with him for defending what the ISESE people did at IMOTA.
    Everybody is Hungry, remember an hungry man is an angry man o

  • @adetutuadegesin7117
    @adetutuadegesin7117 Před měsícem +1

    More wisdom

  • @arinolamayaki7487
    @arinolamayaki7487 Před měsícem +2

    Se ebi o pa awon oloro ni?
    Iru radarada wo niyen, won fe fi oro le awon to fe fi ehonu han.
    Ojo a pa bata, a pa jiwinjiwin eti awon oloro l’Eko.
    Awon alabode!!!

  • @IfaniyiOgunlola
    @IfaniyiOgunlola Před měsícem +3

    Ebí ń pá míì, Oro fẹ́ kè, ṣe ẹni tí Ẹbi ń pá lé gbé Oro nii

  • @owolabichristanah1876
    @owolabichristanah1876 Před měsícem +4

    Corona virus entered Lagos and killed thousands of people Oro could not chase it away 😂

  • @yemireda2057
    @yemireda2057 Před měsícem +3

    Baba mi. Respect all the way. E pe fun wa. Awon agba elebi

  • @emmanuelajayi7715
    @emmanuelajayi7715 Před měsícem +1

    O DARA KI E BA AWON ARA YIN SO OTITO ORO.

  • @abimbolaakingbehin1178
    @abimbolaakingbehin1178 Před měsícem +3

    E ku ognon ati oye Baba ifa. Olodumare a je ko ma ju yin se o. Thanks for the clarification as this exposes those abusing our traditional values for political gains. Well done sir.

  • @akinwunmiolumide7590
    @akinwunmiolumide7590 Před měsícem +1

    EKU OJO META SIR

  • @user-bk1qe4pg3j
    @user-bk1qe4pg3j Před měsícem +1

    O ti to o roo❤❤❤

  • @jamiuomogoriola8300
    @jamiuomogoriola8300 Před měsícem +4

    Babami adeifa iwalesin Erin pami pelu oro tie so pe .. se afi oro le ebi ni

  • @OgunlereTimileyin
    @OgunlereTimileyin Před měsícem

    Modupe baba ❤

  • @afeezlawal3436
    @afeezlawal3436 Před měsícem +2

    Baba Awo mi long time sir

  • @user-tt1ml4yg2g
    @user-tt1ml4yg2g Před měsícem +1

    Elo baba mi onisese ogbo koni ku ma yin ninu eku la Kaye e fe fi abunku ka isese koni baje

  • @racheldavis2554
    @racheldavis2554 Před měsícem +2

    ❤❤❤

  • @04105er
    @04105er Před měsícem

    Lagos Gang......Oro osan gangan.

  • @awaomoyoobatv
    @awaomoyoobatv Před měsícem +1

    Please sir, is there a way to know a true son (Omo OKO) from a bastard child (Omo ale) in the Yoruba way?

  • @oluwasesanajayi2298
    @oluwasesanajayi2298 Před měsícem +1

    Baba edumare bless you sir

  • @myineempire1
    @myineempire1 Před měsícem +2

    KÀBÍYÈSÍ ADÉIFÀ🙇🏽

  • @jamiuomogoriola8300
    @jamiuomogoriola8300 Před měsícem +2

    Ogbo atoo babami adeifa eku lakaye agba ifa ni ona abayowa .. moti lalare ni ojo kini osu keje odun yii .. ifa tiwon da loju ala ni ifa oshe osa ...ni oro nigeria lojutu nimotaji loju orun

  • @sulaimantunrayo
    @sulaimantunrayo Před měsícem +1

    Good talk to you sir

  • @abiolafolorunso5458
    @abiolafolorunso5458 Před měsícem

    Nigba wo loro bere si jade losa ooo?

  • @awaomoyoobatv
    @awaomoyoobatv Před měsícem +1

    Baba mi. Koni baje funyin laye

  • @olatemitope737
    @olatemitope737 Před měsícem

    Oga oooooo.
    During his swear in in abuja they did not call isese ppl. But now they recognize them shame.
    Why can he call Alfas and pastors to start crusade. His wife is a Christian and he himself is imole. So what concerns oro.
    Well oro ppl are poor ppl maybe they gave them little change shame.

  • @emmanuelben-edigbe
    @emmanuelben-edigbe Před měsícem

    What will Olodumare do to this? Yoruba have used their own hand to destroyed their own god😢.

  • @kikelomolafiaji1913
    @kikelomolafiaji1913 Před měsícem

    Eku atunse baba ifa tani komo wipe ise owo ti won gba ni won unse, ti won wa unfi isheshe wa se oselu, oku won oku alale ile Yoruba

  • @oluwatoyinfamodimu1679
    @oluwatoyinfamodimu1679 Před měsícem

    Agba yin a dale baba

  • @olaniran2791
    @olaniran2791 Před měsícem +1

    Ba mi longest time

  • @christaywo1368
    @christaywo1368 Před měsícem +1

    90 billion
    Ebora Owu
    Ifa Eko

  • @SamuelDada-m3c
    @SamuelDada-m3c Před měsícem

    Ejoo emabinu o ejeki oni kaluku se ifehonun hon ni ilu Baba re ki hausa se ifehonun han ni ile hausa ki yibo se ifehonun hon ni ile yibo ki eni ki enikeni ma wa so ilu wa di ibudo Ogun o, we won't allow any tribe to come and destroy our fathers land for us o, or you should go to Abuja and protest there please please and please thank you all

  • @mustaphaabdulrasaq7069
    @mustaphaabdulrasaq7069 Před měsícem

    Is it Oro that cure COVID .

  • @kikelomolafiaji1913
    @kikelomolafiaji1913 Před měsícem

    Otidi abuku toje wipe owo ni won fi unse gbogbo unkan, tinubu deti so wipe what money can not do more money will do it. Ounti ounsele niyen. Awon onile ile Yoruba loma se Idaho awon ti oun fi isese wa se eleya lase edunmare

  • @idrisalooma5120
    @idrisalooma5120 Před měsícem

    DJ WK you see now this area I use to have issue with you people traditionalist if you said they can use oro to pursue ajakale-arun why you people traditionalist don't use oro to pursue COVID-19?

  • @adehamadeham5944
    @adehamadeham5944 Před měsícem

    Gbogbo Onisese ti o satileyin fun Tinubu ti o fi so Ile Yoruba di pakute Iku fun Omo Alade ti E si ni Agbara lati gba Ile Yoruba kuro loko Eru Nigeria sugbon ti E ko nitori Ife ara yin nikan bi O ti le wu ki e lagbara to e ni labo Ire ADABI ti Omo Yoruba ko Pokunso, ku Iku Ebi, won nbe si Omi latari Inira

  • @horlahinksj7644
    @horlahinksj7644 Před měsícem +1

    All significant Traditionalist in Lagos should not allow this hold. That is how they did during election. Same kings and leaders standing against traditional religion are the one using it against the people.
    Politicians doesn't care, we are the ones that shouldn't allow it

    • @loantha2996
      @loantha2996 Před měsícem

      No one gave them 90 billion

    • @horlahinksj7644
      @horlahinksj7644 Před měsícem

      @@loantha2996??

    • @emmanuelben-edigbe
      @emmanuelben-edigbe Před měsícem

      What will Olodumare do to this? Yoruba have used their own hand to destroyed their own god😢.